Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn May
Av. Av. Av. Av.
Iye: Hrs. Mags. R.V. Bi.St.
Aṣá. Àkàn. 369 132.6 13.2 57.2 10.2
Aṣá. Déédéé 22,411 58.9 7.0 22.3 5.4
Aṣá. Olù. 15,550 48.1 4.2 14.4 3.3
Akéde 181,576 10.4 1.0 3.4 1.0
ÀRÒPỌ̀ 219,906 Àwọn Tí A Batisí: 868
Iye 219,906 tó ròyìn ní oṣù May ni iye tó ga jù lọ nínú ọdún iṣẹ́ ìsìn yìí. A ní góńgó tuntun ti 22,411 aṣáájú ọ̀nà déédéé.