ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • km 12/01 ojú ìwé 2
  • Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn August

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn August
  • Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2001
Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2001
km 12/01 ojú ìwé 2

Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn August

Av. Av. Av. Av.

Iye: Hrs. Mags. R.V. Bi.St.

Aṣá. Àkàn. 413 136.2 23.1 63.7 12.8

Aṣá. Déédéé 26,674 52.5 9.7 20.3 5.3

Aṣá. Olù. 5,986 47.6 7.2 14.4 3.9

Akéde 212,605 10.4 2.1 3.7 1.1

ÀRÒPỌ̀ 245,678 Àwọn Tó Ṣèrìbọmi: 635

Góńgó wa tuntun ti 245,678 àwọn akéde tí wọ́n ròyìn ní oṣù August fi 2,924 lé sí ti oṣù July tó kọjá, ó sì fi 8,893 lé sí ti oṣù August 2000. Iye àwọn ìjọ tó jẹ́ 4,457 tí wọ́n ròyìn fi hàn pé a ní ìbísí 103 ní àfikún sí iye àwọn ìjọ tí wọ́n ròyìn ní oṣù August ọdún tó kọjá. Bákan náà, iye àwọn tó wá síbi ìṣe ìrántí ọdún yìí jẹ́ 639,237. Èyí fi 63,707 lé sí iye àwọn tí wọ́n pésẹ̀ ní ọdún 2000, èyí tó jẹ́ 575,530. A gbóríyìn fún àwọn akéde fún ìtara wọn ní ríran àwọn olùfẹ́ òmìnira lọ́wọ́ láti fi Jèhófà ṣe ààbò wọn.—Sm. 31:19.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́