Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ June 8
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ JUNE 8
Orin 14
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
lv-YR àfikún ẹ̀yìn ìwé, ojú ìwé 212 sí 215
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Léfítíkù 1-5
No. 1: Léfítíkù 4:1-15
No. 2: Ǹjẹ́ Ó Yẹ Ká Máa Fọ́nnu? (lr orí 21)
No. 3: Báwo Ló Ṣe Yẹ Káwọn Kristẹni Máa Lo Ọlá-Àṣẹ?
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
Orin 20
5 min: Àwọn ìfilọ̀.
10 min: Ipa Pàtàkì Tí Jésù Ń Kó Nínú Ète Ọlọ́run. Àsọyé tó dá lé ìwé Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run, lábẹ́ ìsọ̀rí tó bẹ̀rẹ̀ lójú ìwé 276.
10 min: Ìwé Tá A Máa Lò Lóṣù June. Ṣàṣefihàn ọ̀nà tó gbéṣẹ́ láti fi fìwé lọni ní ìpínlẹ̀ ìwàásù yín. Tún ṣàṣefihàn bá a ṣe lè fàwọn ìtẹ̀jáde náà lọni nígbà tá a bá ń fi ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lọni.
10 min: “Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Wa Ń Jẹ́ Ká Fi Hàn Pé A Nífẹ̀ẹ́ Ọlọ́run.” Ìbéèrè àti ìdáhùn.
Orin 10