Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ December 7
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ DECEMBER 7
Orin 108
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
lv orí 13 ìpínrọ̀ 16 sí 26, àpótí tó wà lójú ìwé 156
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Joshua 1-5
No. 1: Jóṣúà 5:1-15
No. 2: Ó Yẹ Kí Àwọn Ọ̀rẹ́ Wa Fẹ́ràn Ọlọ́run (lr orí 44)
No. 3: Kí Ni Ìjọba Ọlọ́run? Bí A Ṣe Lè Fi Hàn Pé À Ń Fẹ́ Ẹ (lr orí 45)
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
Orin 64
5 min: Àwọn ìfilọ̀.
10 min: A Ṣètò Wa Láti Ṣiṣẹ́ ní Ìpínlẹ̀ Ìwàásù. A gbé e ka ìwé A Ṣètò Wa, ojú ìwé 102 sí 104. Jíròrò ìpínrọ̀ mẹ́fà tó wà lábẹ́ ìsọ̀rí náà, “Ìpínlẹ̀ Ìwàásù.” Fọ̀rọ̀ wá ọ̀rọ̀ wò lẹ́nu alábòójútó iṣẹ́ ìsìn nípa ètò tí ìjọ ṣe.
10 min: Àwọn ọ̀ràn tó ń fẹ́ àbójútó nínú ìjọ.
10 min: Fòye Mọ Èrò Ọkàn Ẹni Tó Béèrè Ọ̀rọ̀. Ìjíròrò pẹ̀lú àwùjọ, tá a gbé ka ìwé Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run, ojú ìwé 66 sí 68.
Orin 137