Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ June 14
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ JUNE 14
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: 2 Sámúẹ́lì 22-24
No. 1: 2 Sámúẹ́lì 22:1-20
No. 2: Báwo Ni Òfin Ṣe Jẹ́ Akọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Tí Ń Sinni Lọ Sọ́dọ̀ Kristi? (Gál. 3:24)
No. 3: Ayé Kò Ní Pa Run Láé (td 25B)
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
5 min: Àwọn ìfilọ̀.
10 min: Àwọn Àṣeyọrí Wo La Ṣe? Ìjíròrò pẹ̀lú àwùjọ. Gbóríyìn fún ìjọ fún ìgbòkègbodò wọn lásìkò Ìrántí Ikú Kristi, kó o sì sọ àwọn àṣeyọrí tẹ́ ẹ ṣe. Ní kí àwọn ará sọ àwọn ìrírí tí wọ́n ní nígbà tí wọ́n ṣe aṣáájú-ọ̀nà olùrànlọ́wọ́.
10 min: Olùkọ́ Tó Já Fáfá Máa Ń Kọ́ni Láti Máa Fi Ẹ̀kọ́ Sílò. Àsọyé tá a gbé ka ìwé Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run, ojú ìwé 60.
10 min: “Ǹjẹ́ Ojú Rẹ Mú Ọ̀nà Kan?” Ìbéèrè àti ìdáhùn.