Àwọn Kókó Inú Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn
Láàárín oṣù mẹ́sàn-án àkọ́kọ́ nínú ọdún iṣẹ́ ìsìn tá a wà yìí, a ti dá ìjọ tuntun mẹ́tàlélọ́gọ́fà [123] sílẹ̀ ní Nàìjíríà. Ó tún wúni lórí láti rí i pé ní ìpíndọ́gba, igba ó lé márùndínláàádọ́rin [265] èèyàn ló ń ṣèrìbọmi lọ́sọ̀ọ̀sẹ̀.