Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ November 15
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ NOVEMBER 15
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: 1 Kíróníkà 26-29
No. 1: 1 Kíróníkà 29:10-19
No. 2: Kì Í Ṣe Ọlọ́run Kan Náà Ni Gbogbo Èèyàn Ń Sìn (td 34E)
No. 3: Ṣé Gbogbo Àwọn Júù Ló Máa Di Kristẹni?
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
5 min: Àwọn ìfilọ̀.
20 min: “Àsọtẹ́lẹ̀ Bíbélì Ṣeé Gbára Lé, Ìtàn Inú Rẹ̀ sì Péye.” Ìbéèrè àti ìdáhùn. Gẹ́gẹ́ bí àfidípò, ẹ lo ìwé Bíbélì Fi Kọ́ni, orí 2, ìpínrọ̀ 6 sí 17. Ìbéèrè àti ìdáhùn.
10 min: Àpótí Ìbéèrè. Alàgbà ni kó sọ àsọyé yìí.