Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn Ọ̀sẹ̀ Tó Bẹ̀rẹ̀ ní July 29
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ JULY 29
Orin 51 àti Àdúrà
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
jr orí 12 ìpínrọ̀ 14 sí 19 àti àpótí tó wà lójú ìwé 148 (30 min.)
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Ìṣe 26-28 (10 min.)
No. 1: Ìṣe 26:19-32 (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
No. 2: Ogun Amágẹ́dọ́nì Fi Hàn Pé Ọlọ́run Nífẹ̀ẹ́ Wa—td 4B (5 min.)
No. 3: Bí Ẹ̀mí Ọlọ́run Ṣe Ń Ṣiṣẹ́ Lára Àwọn Ìránṣẹ́ Rẹ̀—Gál. 5:22, 23; Ìṣí. 22:17 (5 min.)
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
10 min: Sọ̀rọ̀ Bí Ọlọ́run Ṣe Dá Ọ Tó O Bá Ń Wàásù. Àsọyé tó dá lórí ìwé Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run, ojú ìwé 128, ìpínrọ̀ 1 sí ojú ìwé 129, ìpínrọ̀ 1. Ní ṣókí, fọ̀rọ̀ wá ọ̀rọ̀ wò lẹ́nu akéde kan tó máa ń tijú tẹ́lẹ̀ àmọ́ tó ti wá borí ìṣòro yẹn báyìí. Kí ló jẹ́ kó lè borí ìṣòro yẹn lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù?
10 min: Àpótí Ìbéèrè. Ìjíròrò. Alàgbà ni kó ṣe iṣẹ́ yìí.
10 min: Ẹ Fi Ara Yín Hàn Ní Ọmọ Baba Yín. (Mát. 5:43-45) Ìjíròrò tó dá lórí Ìwé Ọdọọdún 2013, ojú ìwé 89, ìpínrọ̀ 3 sí ojú ìwé 90, ìpínrọ̀ 1 àti ojú ìwé 164, ìpínrọ̀ 1. Ní kí àwọn ará sọ ẹ̀kọ́ tí wọ́n rí kọ́.
Orin 80 àti Àdúrà