Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ June 23
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ JUNE 23
Orin 109 àti Àdúrà
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
cl orí 9 ìpínrọ̀ 1 sí 7 (30 min.)
Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Léfítíkù 10-13 (10 min.)
No. 1: Léfítíkù 12:1–13:8 (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
No. 2: Ṣé Ìsìn Ṣẹ̀ṣẹ̀dé Ni Ìsìn Ẹlẹ́rìí Jèhófà?—td 12A (5 min.)
No. 3: Ìdí Tí Àwọn Èèyàn Fi Ń Ṣàìsàn—lr orí 23 (5 min.)
Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
10 min: Ìwé Tá A Máa Lò Lóṣù July. Ìjíròrò. Ní ṣókí, sọ àwọn kókó pàtàkì tó wà nínú ìwé tá a máa lò, kó o sì ṣe àṣefihàn kan tàbí méjì.
20 min: “Bá A Ṣe Lè Ran Àwọn Tí Kò Fi Bẹ́ẹ̀ Mọ̀wé Kà Lọ́wọ́.” Ìbéèrè àti ìdáhùn.
Orin 55 àti Àdúrà