Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ August 17
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ AUGUST 17
Orin 5 àti Àdúrà
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
cl orí 29 ìpínrọ̀ 1 sí 10 (30 min.)
Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: 2 Àwọn Ọba 1-4 (8 min.)
No. 1: 2 Àwọn Ọba 1:11-18 (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
No. 2: Ìdí Tí Kò Fi Yẹ Ká Jẹ́ Kí Ọkàn Wa Fà Sí Ohun Táa Ti Yááfì Ká Lè Sin Jèhófà—Lúùkù 9:62 (5 min.)
No. 3: Àwọn Ohun Tá A Gbọ́dọ̀ Ṣe Ká Lè Sún Mọ́ Ọlọ́run—igw ojú ìwé 28 ìpínrọ̀ 5 sí ojú ìwé 29 ìpínrọ̀ 3 (5 min.)
Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
ẸṢIN Ọ̀RỌ̀ OṢÙ YÌÍ: “Ní tèmi àti agbo ilé mi, Jèhófà ni àwa yóò máa sìn.” —Jóṣ. 24:15.
30 min: ‘Kí Ọ̀rọ̀ Wọ̀nyí Wà ní Ọkàn Rẹ.’ Ìbéèrè àti ìdáhùn. Ní ṣókí, fi àlàyé tó wà ní ìpínrọ̀ àkọ́kọ́ nasẹ̀ ọ̀rọ̀ rẹ, kí o sì fi àlàyé tó wà ní ìpínrọ̀ tó gbẹ̀yìn parí ọ̀rọ̀ rẹ.
Orin 88 àti Àdúrà