ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 June ojú ìwé 5
  • June 20 Sí 26

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • June 20 Sí 26
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 June ojú ìwé 5

June 20 Sí 26

SÁÀMÙ 45-51

  • Orin 67 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Jèhófà Kò Ní Fi Ẹni Tó Ní Ìròbìnújẹ́ Ọkàn Sílẹ̀”: (10 min.)

    • Sm 51:1-4​—Dáfídì kábàámọ̀ gan-an pé òun dẹ́ṣẹ̀ sí Jèhófà (w93 3/⁠15 ojú ìwé 10 àti 11 ìpínrọ̀ 9 sí 13)

    • Sm 51:7-9​—Dáfídì fẹ́ kí Jèhófà dárí ji òun kó bàa lè máa láyọ̀ bíi ti tẹ́lẹ̀ (w93 3/⁠15 ojú ìwé 12 àti 13 ìpínrọ̀ 18 sí 20)

    • Sm 51:10-17​—Dáfídì mọ̀ pé Jèhófà máa dárí ji ẹni tó bá ronú pìwà dà tọkàntọkàn (w15 6/⁠15 ojú ìwé 14 ìpínrọ̀ 6; w93 3/⁠15 ojú ìwé 14 sí 17 ìpínrọ̀ 4 sí 16)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Sm 45:4​—Òtítọ́ tó ga jù lọ wo la gbọ́dọ̀ gbèjà? (w14 2/⁠15 ojú ìwé 5 ìpínrọ̀ 11)

    • Sm 48:​12, 13—Iṣẹ́ wo ni àwọn ẹsẹ Bíbélì yìí sọ pé a gbọ́dọ̀ ṣe? (w15 7/⁠15 ojú ìwé 9 ìpínrọ̀ 13)

    • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

    • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Sm 49:10–50:6

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) g16.3 ojú ìwé 10 àti 11

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) g16.3 ojú ìwé 10 àti 11

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) fg ẹ̀kọ́ 3 ìpínrọ̀ 1​—⁠Ní ìparí ìkẹ́kọ̀ọ́, jẹ́ kí akẹ́kọ̀ọ́ rẹ wo fídíò tó wà lórí ìkànnì jw.org/⁠yo tá a pè ní Ta ni Òǹṣèwé Bíbélì?

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 98

  • “Ọgọ́rùn-ún Ọdún Ti Kọjá, Ìjọba Ọlọ́run Ṣì Ń Ṣàkóso”: (15 min.) Ìbéèrè àti ìdáhùn. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò tó wà lórí ìkànnì jw.org/⁠yo tá a pè ní Ọgọ́rùn-ún Ọdún Ti Kọjá, Ìjọba Ọlọ́run Ṣì Ń Ṣàkóso láti ìbẹ̀rẹ̀ dé apá tá a pè ní “Ìdálẹ́kọ̀ọ́ Ọlọ́jọ́ Kan.” (Wo abẹ́ ÀWỌN ÌTẸ̀JÁDE > ÀWỌN FÍDÍÒ.)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) ia orí 18 ìpínrọ̀ 1 sí 13

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 109 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́