August 28–September 3
Ìsíkíẹ́lì 39-41
Orin 107 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Bí Ìran Tẹ́ńpìlì Tí Ìsíkíẹ́lì Rí Ṣe Kàn Ọ́”: (10 min.)
Isk 40:2—Ìjọsìn Jèhófà ga ju gbogbo ìjọsìn yòókù lọ (w99 3/1 11 ¶16)
Isk 40:3, 5—Ohun tí Jèhófà ní lọ́kàn nípa ìjọsìn mímọ́ máa ṣẹ (w07 8/1 10 ¶2)
Isk 40:10, 14, 16—Tá a bá fẹ́ kí Jèhófà tẹ́wọ́ gba ìjọsìn wa, a gbọ́dọ̀ máa fi àwọn ìlànà rẹ̀ mímọ́ sílò (w07 8/1 11 ¶4)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Isk 39:7—Tí àwọn èèyàn bá ń dá Ọlọ́run lẹ́bi fún ìwà ìrẹ́jẹ tó kún inú ayé, báwo nìyẹn ṣe ń kó ẹ̀gàn bá orúkọ Ọlọ́run? (w12 9/1 21 ¶2)
Isk 39:9—Lẹ́yìn ogun Amágẹ́dọ́nì, kí ló máa ṣẹlẹ̀ sí àwọn ohun ìjà tí àwọn orílẹ̀-èdè fi sílẹ̀? (w89 8/15 14 ¶20)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Isk 40:32-47
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) fg ẹ̀kọ́ 1 ¶1—Sọ̀rọ̀ ṣókí nípa fídíò Ṣé O Fẹ́ Gbọ́ Ìròyìn Ayọ̀? (àmọ́ ẹ má ṣe wò ó) Fi ìwé náà lọ̀ ọ́.
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) fg ẹ̀kọ́ 1 ¶2—Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) fg ẹ̀kọ́ 1 ¶3-4
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Ìgbà Wo Ni Mo Tún Lè Ṣe Olùrànlọ́wọ́ Aṣáájú-Ọ̀nà?”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà, Lọ́lá Jèhófà, Kò Sóhun Tí Mi Ò Lè Ṣe.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 17 ¶1-9
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 92 àti Àdúrà