TREASURES FROM GOD’S WORD | ÌSÍKÍẸ́LÌ 39-41
Bí Ìran Tẹ́ńpìlì Tí Ìsíkíẹ́lì Rí Ṣe Kàn Ọ́
- Àwọn ìyẹ̀wù tàbí yàrá ẹ̀ṣọ́ àti àwọn òpó gíga ń jẹ́ ká mọ̀ pé Jèhófà ní àwọn ìlànà tó ga fún ìjọsìn rẹ̀ mímọ́ 
- Bi ara rẹ pé, ‘Àwọn nǹkan wo ni mo lè ṣe tó máa fi hàn pé mo fara mọ́ àwọn ìlànà Jèhófà?’