ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | DÁNÍẸ́LÌ 7-9
Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì Sọ Ìgbà Tí Mèsáyà Máa Dé
Bíi Ti Orí Ìwé
	“ÀÁDỌ́RIN Ọ̀SẸ̀” (490 ỌDÚN)
- “Ọ̀SẸ̀ MÉJE” (49 ỌDÚN) - 455 B.C.E. “Ọ̀rọ̀ náà láti mú Jerúsálẹ́mù padà bọ̀ sípò” - 406 B.C.E. Wọ́n tún Jerúsálẹ́mù kọ́ 
- “Ọ̀SẸ̀ MÉJÌ-LÉ-LỌ́GỌ́TA” (434 ỌDÚN) 
- “Ọ̀SẸ̀ KAN” (7 ỌDÚN) - 29 C.E. Mèsáyà dé - 33 C.E. Wọ́n “ké” Mèsáyà kúrò - 36 C.E. Òpin “àádọ́rin ọ̀sẹ̀”