February 19-25
MÁTÍÙ 16-17
- Orin 45 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Èrò Ta Ni Ò Ń Rò?”: (10 min.) - Mt 16:21, 22—Ojú àánú tí kò tọ́ mú kí Pétérù ṣi inú rò (w07 2/15 16 ¶17) 
- Mt 16:23—Èrò Pétérù kò bá ti Ọlọ́run mu (w15 5/15 13 ¶16-17) 
- Mt 16:24—Àwọn Kristẹni gbọ́dọ̀ jẹ́ kí èrò Ọlọ́run máa darí wọn (w06 4/1 23 ¶9) 
 
- Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.) - Mt 16:18—Ta ni àpáta náà tí Jésù kọ́ ìjọ Kristẹni sórí rẹ̀? (“Ìwọ ni Pétérù, orí àpáta yìí,” “ìjọ” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Mt 16:18, nwtsty) 
- Mt 16:19—Kí ni “àwọn kọ́kọ́rọ́ Ìjọba ọ̀run” tí Jésù fún Pétérù? (“àwọn kọ́kọ́rọ́ Ìjọba ọ̀run” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Mt 16:19, nwtsty) 
- Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà? 
- Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Mt 16:1-20 
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Dáhùn ìbéèrè kan táwọn èèyàn sábà máa ń béèrè tí wọn kò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù ní ìpínlẹ̀ yín. 
- Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. 
- Ìpadàbẹ̀wò Kejì—Fídíò: (5 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀. 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- “Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I—Máa Lo Ìbéèrè Lọ́nà Tó Gbéṣẹ́”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Ṣe Iṣẹ́ Tí Jésù Ṣe—Máa Kọ́ni. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lv orí 4 ¶12-21 àti àpótí Àṣẹ Ta Ló Yẹ Kí N Tẹ̀ Lé? 
- Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.) 
- Orin 134 àti Àdúrà