September 3-9
JÒHÁNÙ 1-2
- Orin 13 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Iṣẹ́ Ìyanu Àkọ́kọ́ Tí Jésù Ṣe”: (10 min.) - [Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Jòhánù.] 
- Jo 2:1-3—Ohun tó lè dójú tini ṣẹlẹ̀ níbí àsè ìgbéyàwó kan (w15 6/15 4 ¶3) 
- Jo 2:4-11—Ohun tí Jésù ṣe mú kí ìgbàgbọ́ àwọn ọmọlẹ́yìn rẹ̀ túbọ̀ lágbára (jy 41 ¶6) 
 
- Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.) - Jo 1:1—Kí nìdí tá a fi gbà pé Jòhánù kò sọ pé ìkan náà ni “Ọ̀rọ̀ náà” àti Ọlọ́run Olódùmarè? (“ọ̀rọ̀ náà,” “pẹ̀lú,” “ọ̀rọ̀ náà sì jẹ́ ọlọ́run kan” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Jo 1:1, nwtsty) 
- Jo 1:29—Kí nìdí tí Jòhánù Arinibọmi fi pe Jésù ní “Ọ̀dọ́ Àgùntàn Ọlọ́run”? (“ọ̀dọ́ Àgùntàn Ọlọ́run” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Jo 1:29, nwtsty) 
- Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà? 
- Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jo 1:1-18 
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Nígbà Àkọ́kọ́—Fídíò: (4 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀. 
- Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Wo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh 41 ¶10-11 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (8 min.) 
- Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe: (7 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe ti oṣù September. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lv orí 12 ¶9-14 
- Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.) 
- Orin 121 àti Àdúrà