ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb18 October ojú ìwé 2
  • October 1-7

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • October 1-7
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
  • Ìsọ̀rí
  • MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
mwb18 October ojú ìwé 2

October 1-7

JÒHÁNÙ 9-10

  • Orin 25 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Jésù Ń Bójú Tó Àwọn Àgùntàn Rẹ̀”: (10 min.)

    • Jo 10:1-3, 11, 14​—Jésù ni “olùṣọ́ àgùntàn àtàtà,” ó mọ àwọn àgùntàn rẹ̀ ní kọ̀ọ̀kan, ó sì máa ń pèsè ohun tí wọ́n nílò lọ́pọ̀ yanturu (“Ọgbà Àgùntàn” àwòrán àti fídíò lórí Jo 10:1, nwtsty; w11 5/15 7-8 ¶5)

    • Jo 10:4, 5​—Àwọn àgùntàn Jésù dá ohùn rẹ̀ mọ̀, wọn ò mọ ohùn ẹlòmíì (cf 124-125 ¶17)

    • Jo 10:16​—Àwọn àgùntàn Jésù wà ní ìṣọ̀kan (“mú wá” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Jo 10:16, nwtsty)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Jo 9:38​—Ọ̀nà wo ni ọkùnrin afọ́jú tó ń tọrọ bárà yẹn gbà wárí fún Jésù? (“wárí fún un” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Jo 9:38, nwtsty)

    • Jo 10:22​—Kí ni Àjọyọ̀ Ìyàsímímọ́? (“Àjọyọ̀ Ìyàsímímọ́” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Jo 10:22, nwtsty)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jo 9:1-17

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́​—Fídíò: (4 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.

  • Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) fg ẹ̀kọ́ 14 ¶1-2

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 62

  • Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (15 min.)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lv orí 13 ¶16-26 àti àpótí Ìjọsìn Tòótọ́ Máa Ń Fúnni Láyọ̀ Tí Kò Lẹ́gbẹ́ [Kò pọn dandan kẹ́ ẹ ka àpótí tàbí àfikún àlàyé]

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 3 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́