February 4-10
RÓÒMÙ 1-3
- Orin 88 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Máa Kọ́ Ẹ̀rí Ọkàn Rẹ”: (10 min.) - [Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Róòmù.] 
- Ro 2:14, 15—Gbogbo èèyàn ló ní ẹ̀rí ọkàn (lv 16 ¶6) 
- Ro 2:15—Kí ẹ̀rí ọkàn wa tó lè tọ́ wa sọ́nà, a gbọ́dọ̀ kọ́ ọ (lv 17-18 ¶8-9) 
 
- Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.) - Ro 3:4—Báwo la ṣe lè “jẹ́ kí a rí Ọlọ́run ní olóòótọ́”? (w08 6/15 30 ¶5) 
- Ro 3:24, 25—Báwo ni “ìràpadà tí Kristi Jésù san” ṣe lè bo “ẹ̀ṣẹ̀ tí ó wáyé ní ìgbà tí ó ti kọjá” mọ́lẹ̀? (w08 6/15 29 ¶6) 
- Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà? 
- Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ro 1:1-17 (th ẹ̀kọ́ 10) 
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Tẹra Mọ́ Kíkàwé àti Kíkọ́ni: (10 min.) Ìjíròrò. Ẹ wo fídíò náà, Sọ̀rọ̀ Bí Ẹni Ń Báni Fọ̀rọ̀ Wérọ̀, lẹ́yìn náà, ẹ jíròrò ẹ̀kọ́ 2 nínú ìwé pẹlẹbẹ Kíkọ́ni. 
- Àsọyé: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) w06 6/1 12-13—Àkòrí: Máa Rántí Pé Ó Níbi Tágbára Rẹ àti Tàwọn Míì Mọ. (th ẹ̀kọ́ 7) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- “Ṣé O Máa Ń Rí Àwọn Ànímọ́ Ọlọ́run Tí A Kò Lè Rí?”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà, Àwọn Ìṣẹ̀dá Ọlọ́run Ń Fi Ògo Rẹ̀ Hàn—Ìmọ́lẹ̀ àti Àwọ̀. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 2 Àfikún Jésù Kristi Ni Mèsáyà Tí Ọlọ́run Ṣèlérí 
- Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.) 
- Orin 142 àti Àdúrà