February 11-17
RÓÒMÙ 4-6
- Orin 20 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Ọlọ́run Dámọ̀ràn Ìfẹ́ Tirẹ̀ fún Wa”: (10 min.) - Ro 5:8, 12—Jèhófà nífẹ̀ẹ́ wa “nígbà tí àwa ṣì jẹ́ ẹlẹ́ṣẹ̀” (w11 6/15 12 ¶5) 
- Ro 5:13, 14—Ẹ̀ṣẹ̀ àti ikú ń jọba (w11 6/15 12 ¶6) 
- Ro 5:18, 21—Jèhófà rán Ọmọ rẹ̀ wá sáyé ká lè ní ìyè (w11 6/15 13 ¶9-10) 
 
- Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.) - Ro 6:3-5—Kí ni ìbatisí “sínú Kristi Jésù” àti ìbatisí “sínú ikú rẹ̀” túmọ̀ sí? (w08 6/15 29 ¶7) 
- Ro 6:7—Kí nìdí tí Ọlọ́run ò fi ní fi ẹ̀ṣẹ̀ táwọn èèyàn dá kí wọ́n tó kú dá wọn lẹ́jọ́? (w14 6/1 11 ¶1) 
- Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà? 
- Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ro 4:1-15 (th ẹ̀kọ́ 10) 
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Nígbà Àkọ́kọ́—Fídíò: (4 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀. 
- Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. (th ẹ̀kọ́ 4) 
- Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. Onílé sọ ohun táwọn èèyàn sábà máa ń sọ ní ìpínlẹ̀ yín tí wọn kò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù. Fèsì ní ṣókí, kó o sì máa bá ọ̀rọ̀ rẹ lọ. (th ẹ̀kọ́ 6) 
- Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. Fi ọ̀kan lára ìtẹ̀jáde tó wà nínú Àpótí Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ hàn án. (th ẹ̀kọ́ 9) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (15 min.) 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 2 ¶17-20 
- Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.) 
- Orin 97 àti Àdúrà