June 10-16
ÉFÉSÙ 1-3
- Orin 112 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Iṣẹ́ Àbójútó Jèhófà àti Ohun Tó Wà Fún”: (10 min.) - [Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Éfésù.] 
- Ef 1:8, 9—Ìjọba Mèsáyà wà lára “àṣírí mímọ́” náà (it-2 837 ¶4) 
- Ef 1:10—Jèhófà ń mú kí gbogbo ẹ̀dá rẹ̀ olóye wà ní ìṣọ̀kan (w12 7/15 27-28 ¶3-4) 
 
- Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.) - Ef 3:13—Ọ̀nà wo ni àwọn ìpọ́njú Pọ́ọ̀lù gbà “yọrí sí ògo” fún àwọn Kristẹni tó wà ní Éfésù? (w13 2/15 28 ¶15) 
- Ef 3:19—Kí ló túmọ̀ sí láti “mọ ìfẹ́ Kristi”? (cl 299 ¶21) 
- Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà? 
- Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ef 1:1-14 (th ẹ̀kọ́ 5) 
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Nígbà Àkọ́kọ́—Fídíò: (4 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀. 
- Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. (th ẹ̀kọ́ 1) 
- Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. Onílé sọ ohun táwọn èèyàn sábà máa ń sọ ní ìpínlẹ̀ yín tí wọn kò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù. Fèsì ní ṣókí, kó o sì máa bá ọ̀rọ̀ rẹ lọ. (th ẹ̀kọ́ 3) 
- Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. Fi ọ̀kan lára ìtẹ̀jáde tó wà nínú Àpótí Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ hàn án. (th ẹ̀kọ́ 9) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- “Jẹ́ Kí Ìdákẹ́kọ̀ọ́ Rẹ Túbọ̀ Máa Mérè Wá”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ẹ Di “Ọ̀rọ̀ Ìyè Mú Ṣinṣin”—Ẹ Máa Ṣe Ìdákẹ́kọ̀ọ́ Tó Jíire. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 7 ¶1-8 
- Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.) 
- Orin 144 àti Àdúrà