October 26–November 1
Ẹ́KÍSÓDÙ 37-38
- Orin 43 àti Àdúrà 
- Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.) 
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
- “Ohun Tí Pẹpẹ Àgọ́ Ìjọsìn Wà Fún”: (10 min.) - Ẹk 37:25—Ibi Mímọ́ ni wọ́n gbé pẹpẹ tùràrí sí (it-1 82 ¶3) 
- Ẹk 37:29—Wọ́n po àwọn èròjà tí wọ́n fi ṣe tùràrí mímọ́ pọ̀ dáadáa (it-1 1195) 
- Ẹk 38:1—Inú àgbàlá àgọ́ ìjọsìn ni wọ́n gbé pẹpẹ ẹbọ sísun sí (it-1 82 ¶1) 
 
- Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.) - Ẹk 37:1, 10, 25—Kí nìdí tó fi jẹ́ pé igi bọn-ọ̀n-ní ni wọ́n fi ṣe àgọ́ ìjọsìn? (it-1 36) 
- Ẹk 38:8—Kí ni ìyàtọ̀ tó wà nínú dígí tí wọ́n ń lò láyé ìgbà tí wọ́n ń kọ Bíbélì àti tòde òní? (w15 4/1 15 ¶4) 
- Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì? 
 
- Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ẹk 37:1-24 (th ẹ̀kọ́ 5) 
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
- Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Onílé sọ ohun táwọn èèyàn sábà máa ń sọ ní ìpínlẹ̀ yín tí wọn kò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù. Fèsì ní ṣókí, kó o sì máa bá ọ̀rọ̀ rẹ lọ. (th ẹ̀kọ́ 3) 
- Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Lẹ́yìn náà, fún onílé ní ọ̀kan lára ìtẹ̀jáde wa tó ṣẹ̀ṣẹ̀ jáde, tó sọ̀rọ̀ nípa kókó tí onílé sọ. (th ẹ̀kọ́ 12) 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bhs 199 ¶8-9 (th ẹ̀kọ́ 7) 
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
- Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (5 min.) 
- “Àkànṣe Ìwàásù Tá A Máa Ṣe ní Oṣù November Láti Kéde Ìjọba Ọlọ́run”: (10 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò nígbà àkọ́kọ́ ti oṣù November. 
- Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) jy orí 138 
- Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 
- Orin 22 àti Àdúrà