November 27–December 3
JÓÒBÙ 20-21
Orin 38 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Owó Kọ́ Ló Ń Mú Kéèyàn Jẹ́ Olódodo”: (10 min.)
Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)
Job 20:2—Kí làwọn alàgbà lè ṣe láti ran àwọn tó ní ìdààmú ọkàn lọ́wọ́? (w95 1/1 9 ¶19)
Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) Job 20:1-22 (th ẹ̀kọ́ 5)
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o lò. (th ẹ̀kọ́ 1)
Ìpadàbẹ̀wò: (5 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Fún ẹni náà ní ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì, kó o sì fi bá a ṣe máa ń ṣe ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì hàn án. (th ẹ̀kọ́ 6)
Àsọyé: (5 min.) g 7/09 10-11—Àkòrí: Ṣé Ọlọ́run Fẹ́ Kó O Di Ọlọ́rọ̀? (th ẹ̀kọ́ 17)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Ẹ ‘Jẹ́ Kí Àwọn Nǹkan Tó Wà Báyìí Tẹ́ Yín Lọ́rùn’”: (15 min.) Ìjíròrò àti fídíò.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bt orí 2 ¶16-23
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 103 àti Àdúrà