SEPTEMBER 8-14
ÒWE 30
Orin 136 àti Àdúrà | Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
1. “Má Ṣe Fún Mi Ní Òṣì Tàbí Ọrọ̀”
(10 min.)
Ọrọ̀ kò lè fúnni ní ayọ̀ tòótọ́, àmọ́ téèyàn bá gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà, á ní ayọ̀ tòótọ́ (Owe 30:8, 9; w18.01 24-25 ¶10-12)
Olójúkòkòrò kì í ní ìtẹ́lọ́rùn (Owe 30:15, 16; w17.05 26 ¶15-17)
Tó o bá ń tẹ̀ lé ìlànà Bíbélì, o ò ní tọrùn bọ gbèsè, ọkàn ẹ á sì balẹ̀ (Owe 30:24, 25; w11 6/1 10 ¶3)
OHUN TẸ́ Ẹ LÈ ṢE NÍGBÀ ÌJỌSÌN ÌDÍLÉ: Ẹ jíròrò bí ọ̀rọ̀ owó ṣe máa ń rí lára ẹnì kọ̀ọ̀kan yín.—w24.06 13 ¶18.
2. Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì
(10 min.)
Owe 30:26—Kí la rí kọ́ lára àwọn gara orí àpáta? (w09 4/15 17 ¶11-13)
Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí tí wàá fẹ́ sọ?
3. Bíbélì Kíkà
(4 min.) Owe 30:1-14 (th ẹ̀kọ́ 2)
4. Bá A Ṣe Lè Bẹ̀rẹ̀ Ọ̀rọ̀ Wa
(4 min.) ÌWÀÁSÙ ILÉ-DÉ-ILÉ. Fi Ilé Ìṣọ́ No. 1 2025 wàásù fẹ́nì kan. (lmd ẹ̀kọ́ 1 kókó 3)
5. Pa Dà Lọ
(4 min.) ÌWÀÁSÙ NÍBI TÍ ÈRÒ PỌ̀ SÍ. (lmd ẹ̀kọ́ 9 kókó 3)
6. Ṣàlàyé Ohun Tó O Gbà Gbọ́
(4 min.) Àsọyé. ijwbq àpilẹ̀kọ 102—Àkòrí: Ṣé Ẹ̀ṣẹ̀ Ni Tẹ́tẹ́ Títa? (th ẹ̀kọ́ 7)
Orin 80
7. Má Ṣe Jẹ́ Kí Ohun Tí Ayé Ń Pè Ní Àlàáfíà Tàn Ẹ́ Jẹ!—Chibisa Selemani
(5 min.) Ìjíròrò.
Jẹ́ kí àwọn ará wo FÍDÍÒ náà. Lẹ́yìn náà, béèrè pé:
Kí lo rí kọ́ nínú ìrírí Arákùnrin Selemani tó máa jẹ́ kó o ṣèpinnu táá fi ẹ́ lọ́kàn balẹ̀, tí wàá sì ní ìtẹ́lọ́rùn?
8. Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe ti oṣù September
(10 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo FÍDÍÒ náà.
9. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ
(30 min.) lfb ẹ̀kọ́ 16-17