Àwọn Ohun Tó Wà Lórí Ìkànnì JW.ORG
BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ
“Ohun Tí Ò Yé Mi Pọ̀ Ju Èyí Tó Yé Mi Lọ”
Kí ló jẹ́ kí Mario tó jẹ́ pásítọ̀ tẹ́lẹ̀ gbà pé àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ló ń fi òtítọ́ Bíbélì kọ́ni?
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí OHUN TÁ A NÍ > OHUN TÓ WÀ LÓRÍ ÌKÀNNÌ > BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ.
TA LÓ ṢIṢẸ́ ÀRÀ YÌÍ?
Kí ló mú kí eyín ìgbín limpet lágbára ju okùn aláǹtakùn lọ?
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí OHUN TÁ A NÍ > OHUN TÓ WÀ LÓRÍ ÌKÀNNÌ > TA LÓ ṢIṢẸ́ ÀRÀ YÌÍ?