Atọ́ka Àwọn Àkòrí Ilé Ìṣọ́ Àti Jí! 2020
Ó ń tọ́ka sí ìwé ìròyìn tí àpilẹ̀kọ kọ̀ọ̀kan ti jáde
ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
ÀWA ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ
- 1920—Ní Ọgọ́rùn-ún Ọdún Sẹ́yìn, Oct. 
- Kí Ni Wàá Ṣe Tí Kàkàkí Bá Dún? June 
- Òjò Ìbùkún Rọ̀ Sórí Àwọn Tó Pa Dà sí Ìlú Ìbílẹ̀ Wọn, Nov. 
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
- A Máa Bá Yín Lọ, Jan. 
- A Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà Baba Wa Gan-an, Feb. 
- Àjíǹde Dájú! Dec. 
- Bá A Ṣe Lè Ran Àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Wa Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Ṣèrìbọmi—Apá Kìíní, Oct. 
- Bá A Ṣe Lè Ran Àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Wa Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Ṣèrìbọmi—Apá Kejì, Oct. 
- Bá A Ṣe Lè Ran Àwọn Míì Lọ́wọ́ Láti Máa Pa Àṣẹ Kristi Mọ́, Nov. 
- “Báwo Ni Àwọn Òkú Ṣe Máa Jíǹde?” Dec. 
- Bó O Ṣe Lè Borí Ìrẹ̀wẹ̀sì, Dec. 
- “Èmi Fúnra Mi Yóò Wá Àwọn Àgùntàn Mi,” June 
- Ẹ Máa Fún Àwọn Arábìnrin Níṣìírí, Sept. 
- Ẹ Máa Rìn Nínú Òtítọ́, July 
- Ẹ Ní Ìfẹ́ Tó Jinlẹ̀ sí Ara Yín, Mar. 
- “Ẹ Pa Dà Sọ́dọ̀ Mi,” June 
- “Ẹ̀mí Fúnra Rẹ̀ Ń Jẹ́rìí,” Jan. 
- “Fún Mi Ní Ọkàn Tó Pa Pọ̀ Kí N Lè Máa Bẹ̀rù Orúkọ Rẹ,” June 
- Gbogbo Wa La Wúlò Nínú Ìjọ! Aug. 
- Ìgbà Wo Ló Tọ́ Pé Kéèyàn Sọ̀rọ̀? Mar. 
- Ìgbéjàkò Láti Apá Àríwá! Apr. 
- Ìrètí Àjíǹde Jẹ́ Ká Rí I Pé Jèhófà Jẹ́ Onífẹ̀ẹ́, Ọlọ́gbọ́n àti Onísùúrù, Aug. 
- Jèhófà Baba Wa Ọ̀run Nífẹ̀ẹ́ Wa Gan-an, Feb. 
- Jèhófà Ló Ń Darí Ètò Rẹ̀, Oct. 
- Jèhófà Ń Tu Àwọn Tó Rẹ̀wẹ̀sì Nínú, Dec. 
- Jèhófà Nífẹ̀ẹ́ Rẹ, Ó sì Mọyì Ẹ Gan-an! Jan. 
- Jẹ́ Kí Jèhófà Tù Ẹ́ Lára, Feb. 
- Jẹ́ Kí Òtítọ́ Tó O Gbà Gbọ́ Dá Ẹ Lójú, July 
- Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀ Kó O sì Mọ̀wọ̀n Ara Rẹ Bí O Ṣe Ń Bá Ọlọ́run Rẹ Rìn, Aug. 
- Jẹ́ Ọlọ́gbọ́n ní Àkókò Àlàáfíà, Sept. 
- “Kí Orúkọ Rẹ Di Mímọ́,” June 
- ‘Má Ṣe Dẹwọ́’ Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìwàásù, Sept. 
- Má Ṣe Ro Ara Rẹ Ju Bó Ṣe Yẹ Lọ, July 
- “Máa Ṣọ́ Ohun Tí A Fi sí Ìkáwọ́ Rẹ,” Sept. 
- “Mo Pè Yín Ní Ọ̀rẹ́,” Apr. 
- Mọ́kàn Le—Jèhófà Ni Olùrànlọ́wọ́ Rẹ, Nov. 
- Mọyì Àwọn Ìṣúra Tí Kò Ṣeé Fojú Rí, May 
- Mọyì Àwọn Míì Nínú Ìjọ, Aug. 
- “Nígbà Tí Mo Bá Jẹ́ Aláìlera, Ìgbà Náà Ni Mo Di Alágbára,” July 
- O Lè Jẹ́ Ẹlẹ́mìí Àlàáfíà Tó O Bá Sapá Láti Borí Ìlara, Feb. 
- O Lè Jẹ́ “Orísun Ìtùnú” Fáwọn Míì, Jan. 
- Ojú Wo Lo Fi Ń Wo Àwọn Tó Wà ní Ìpínlẹ̀ Ìwàásù Rẹ? Apr. 
- “Ọba Àríwá” Ní Àkókò Òpin Yìí, May 
- Ọjọ́ Iwájú Ni Kó O Tẹjú Mọ́, Nov. 
- “Sá Eré Ìje Náà Dé Ìparí,” Apr. 
- Ṣé O Mọyì Àwọn Ẹ̀bùn Tí Ọlọ́run Fún Ẹ? May 
- Ṣé O Múra Tán Láti Di Apẹja Èèyàn? Sept. 
- Ṣé Ò Ń Retí “Ìlú Tó Ní Ìpìlẹ̀ Tòótọ́”? Aug. 
- Ṣé O Ti Ṣe Tán Láti Ṣèrìbọmi? Mar. 
- Ṣé Wàá Máa Ṣe Ìyípadà Tó Yẹ? Nov. 
- Ṣé Wọ́n Máa Sin Jèhófà Tí Wọ́n Bá Dàgbà? Oct. 
- Ta Ni “Ọba Àríwá” Lónìí? May 
- Tó O Bá Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà Tó O sì Mọyì Rẹ̀, Wàá Ṣèrìbọmi, Mar. 
- “Torí Náà, Ẹ Lọ, Kí Ẹ Máa Sọ Àwọn Èèyàn Di Ọmọ Ẹ̀yìn,”Jan. 
- Túbọ̀ Mọ Àwọn Ará, Kó O sì Máa Gba Tiwọn Rò, Apr. 
BÍBÉLÌ
- Kí Làwọn Awalẹ̀pìtàn Jẹ́ Ká Mọ̀ Nípa Bẹliṣásárì? Feb. 
ÌBÉÈRÈ LÁTI ỌWỌ́ ÀWỌN ÒǸKÀWÉ
- Àwọn wo ni ẹ̀ṣọ́ tẹ́ńpìlì, iṣẹ́ wo ni wọ́n sì ń ṣe? Mar. 
- Ìgbà wo ni Jésù di Àlùfáà Àgbà, ìgbà wo sì ni májẹ̀mú tuntun fìdí múlẹ̀? July 
- Ṣé àwọn ànímọ́ mẹ́sàn-án tó wà nínú Gálátíà 5:22, 23 nìkan ni “èso ti ẹ̀mí”? June 
- Ṣé àwọn èèyàn tó ń ṣàkóso nìkan ni Oníwàásù 5:8 ń tọ́ka sí àbí ó kan Jèhófà náà? Sept. 
- Ṣé ohun tí 1 Kọ́ríńtì 15:29 sọ ni pé àwọn Kristẹni kan ṣèrìbọmi nítorí àwọn òkú? Dec. 
ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI ÀNÍMỌ́ KRISTẸNI
- Fi Gbogbo Ọkàn Rẹ sí Iṣẹ́ Ìsìn Rẹ! Dec. 
- Ìkóra-Ẹni-Níjàánu—Ànímọ́ Táá Jẹ́ Ká Rí Ojúure Jèhófà, June 
- Ìwà Tútù—Báwo Ló Ṣe Ń Ṣe Wá Láǹfààní? May 
ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ
- “Àwa Nìyí! Rán Wa!” (J. àti M. Bergame), Mar. 
- “Jèhófà Ò Gbàgbé Mi” (M. Herman), Nov. 
- Mo Rí Ọ̀pọ̀ Ìbùkún Gbà Torí Mo Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Tó Fi Àpẹẹrẹ Tó Dáa Lélẹ̀ (L. Crépeault), Feb. 
- Ohun Tó Yẹ Kí N Ṣe Ni Mo Ṣe (D. Ridley), July 
Ọ̀KAN-Ò-JỌ̀KAN
- Àwọn Ọba Tó Ń Bára Wọn Jà Lákòókò Òpin Yìí, May 
- Ẹ̀rí Tó Fi Hàn Pé Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì Jẹ́ Ẹrú Nílẹ̀ Íjíbítì, Mar.