ATỌ́KA ÀWỌN ÀKÒRÍ ILÉ ÌṢỌ́ ÀTI JÍ! 2021
Ó ń tọ́ka sí ìwé ìròyìn tí àpilẹ̀kọ kọ̀ọ̀kan ti jáde
ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
ÀWA ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ
- 1921—Ní Ọgọ́rùn-ún Ọdún Sẹ́yìn, Oct. 
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
- Bá A Ṣe Lè Máa Láyọ̀ Tá A Bá Ń Fara Da Ìṣòro, Feb. 
- Báwo La Ṣe Lè Tọ́ Oore Jèhófà Wò? Aug. 
- Báwo Ni Ìfẹ́ Jèhófà Tí Kì Í Yẹ̀ Ṣe Ń Ṣe Ọ́ Láǹfààní? Nov. 
- Bí Gbogbo Ìjọ Ṣe Lè Mú Kí Akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Kan Tẹ̀ Síwájú Kó sì Ṣèrìbọmi, Mar. 
- Bí Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Ṣe Lè Mú Kó O Fara Da Ìṣòro, Mar. 
- “Èmi Yóò Mi Gbogbo Orílẹ̀-Èdè Jìgìjìgì” Sept. 
- Ẹ Di Ẹ̀kọ́ Òtítọ́ Tó Dá Yín Lójú Mú Ṣinṣin, Oct. 
- “Ẹ Gbọ́dọ̀ Jẹ́ Mímọ́,” Dec. 
- Ẹ Jẹ́ Kí Ìfẹ́ Tẹ́ Ẹ Ní fún Ara Yín Túbọ̀ Jinlẹ̀, Jan. 
- Ẹ Má Ṣe Jẹ́ Kó Rẹ̀ Yín! Oct. 
- Ẹ Má Ṣe Máa Bá Ara Yín Díje, Àlàáfíà Ni Kí Ẹ Máa Wá, July 
- Ẹ Máa ‘Fetí sí Jésù,’ Dec. 
- Ẹ Máa Fetí sí Ohùn Olùṣọ́ Àgùntàn Rere, Dec. 
- Ẹ Máa Fi Ìfẹ́ Tí Kì Í Yẹ̀ Hàn sí Ara Yín, Nov. 
- Ẹ̀yin Ọ̀dọ́kùnrin, Ẹ Ṣe Ohun Tó Máa Jẹ́ Káwọn Míì Fọkàn Tán Yín Mar. 
- Ẹ̀yin Tẹ́ Ẹ Ṣẹ̀ṣẹ̀ Ṣègbéyàwó, Ẹ Fi Ìgbésí Ayé Yín Ṣe Iṣẹ́ Ìsìn Jèhófà, Nov. 
- Fara Balẹ̀, Kó O sì Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà, Jan. 
- Fọkàn Balẹ̀, Jèhófà Wà Pẹ̀lú Rẹ, June 
- Ìfẹ́ Ń Jẹ́ Ká Lè Fara Da Ìkórìíra, Mar. 
- Jèhófà Máa Dáàbò Bò Ẹ́—Lọ́nà Wo? Mar. 
- Jèhófà Máa Fún Ẹ Lókun, May 
- Jẹ́ Kí Àǹfààní Iṣẹ́ Ìsìn Tó O Ní Máa Múnú Rẹ Dùn, Aug. 
- Jẹ́ Kí Ìfẹ́ Tó O Ní fún Jèhófà Àtàwọn Ará Túbọ̀ Jinlẹ̀, Sept. 
- Jẹ́ Kí Ìtẹ̀síwájú Rẹ Máa Múnú Rẹ Dùn! July 
- Jẹ́ Kó Túbọ̀ Dá Ẹ Lójú Pé Ẹlẹ́dàá Wà, Aug. 
- Kẹ́kọ̀ọ́ Lára “Ọmọ Ẹ̀yìn Tí Jésù Nífẹ̀ẹ́,” Jan. 
- Kí Ló Ń Fi Hàn Pé Ẹnì Kan Ti Ronú Pìwà Dà Tọkàntọkàn? Oct. 
- Kò Sí Ohun Tó Lè Mú Kí Olódodo Kọsẹ̀, May 
- Má Jẹ́ Kó Sú Ẹ Tó Bá Ṣòro Láti Wàásù Lágbègbè Yín, May 
- Má Ṣe Mú Kí “Àwọn Ẹni Kékeré Yìí” Kọsẹ̀ June 
- Máa Fi Hàn Pé O Mọyì Ìràpadà Nígbà Gbogbo, Apr. 
- Mọyì Àǹfààní Tó O Ní Pé O Wà Nínú Ìdílé Jèhófà, Aug. 
- Mọyì Àwọn Ọ̀dọ́ Tó Wà Nínú Ìjọ, Sept. 
- Mọyì Ipò Orí Tí Jèhófà Ṣètò Nínú Ìjọ, Feb. 
- Ǹjẹ́ O Mọyì Àwọn Àgbàlagbà Tó Wà Láàárín Wa, Sept. 
- Ogunlọ́gọ̀ Èèyàn ti Àgùntàn Mìíràn Ń Yin Jèhófà àti Kristi, Jan. 
- Ohun Tá A Rí Kọ́ Nínú Àwọn Ọ̀rọ̀ Tí Jésù Sọ Kẹ́yìn, Apr. 
- Ohun Tí Ìwé Léfítíkù Kọ́ Wa Nípa Bó Ṣe Yẹ Ká Máa Ṣe Sáwọn Èèyàn, Dec. 
- O Lè Bọ́ Lọ́wọ́ Ìdẹkùn Èṣù! June 
- O Lè Jẹ́ Olóòótọ́ Tí Èèyàn Ẹ Kan Bá Fi Jèhófà Sílẹ̀, Sept. 
- “Orí Gbogbo Ọkùnrin Ni Kristi” Feb. 
- “Orí Obìnrin Ni Ọkùnrin”Feb. 
- O Ṣeyebíye Gan-an Lójú Jèhófà! Apr. 
- Ọlọ́run “Tí Àánú Rẹ̀ Pọ̀” Là Ń Sìn, Oct. 
- Ran Àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Rẹ Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Ṣèrìbọmi, June 
- Ṣé Ìwọ Náà Lè Sọ Àwọn Èèyàn Di Ọmọ Ẹ̀yìn? July 
- Ṣé O Máa Ń Fara Dà Á Bíi Ti Jèhófà? July 
- Ṣé O Ní Ìgbàgbọ́ Tó Lágbára Tó? Nov. 
- Ṣé Wàá Dúró De Jèhófà? Aug. 
- Ṣé Wàá Jẹ́ Kí Ọ̀rọ̀ Nípa Jésù Mú Kó O Kọsẹ̀? May 
- “Tọ Ipasẹ̀ Rẹ̀ Pẹ́kípẹ́kí,” Apr. 
BÍBÉLÌ
- Báwo ni ọ̀rọ̀ tí wọ́n kọ sára òkúta kan láyé àtijọ́ ṣe fi hàn pé òótọ́ ni ọ̀rọ̀ inú Bíbélì? Jan. 
ÌBÉÈRÈ LÁTI ỌWỌ́ ÀWỌN ÒǸKÀWÉ
- Kí ni àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù ní lọ́kàn nígbà tó sọ pé: “Nípasẹ̀ òfin, mo ti di òkú sí òfin”? (Gál. 2:19), June 
- Kí ni òfin tó sọ pé ká má “dìde lòdì sí ẹ̀mí ẹnì kejì” wa túmọ̀ sí? (Léf. 19:16) Dec. 
- Kí nìdí tí Jésù fi sọ ohun tó wà nínú Sáàmù 22:1 ṣáájú ikú rẹ̀? Apr. 
- Kí nìdí tó fi yẹ káwa Kristẹni máa ṣọ́ra tá a bá ń lo àwọn ètò ìṣiṣẹ́ tí wọ́n fi ń fọ̀rọ̀ ránṣẹ́? Mar. 
- Ṣé ó yẹ káwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa lo ìkànnì àwọn tó ń wá ọkọ tàbí ìyàwó láti wá ẹni tá a máa fẹ́? July 
ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI ÀNÍMỌ́ KRISTẸNI
ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ
- A Pinnu Pé A Ò Ní Kọ Iṣẹ́ Tí Jèhófà Bá Fún Wa (K. Logan), Jan. 
- Jèhófà ‘Mú Kí Àwọn Ọ̀nà Mi Tọ́’ (S. Hardy), Feb. 
- Mo Gbádùn Ayé Mi Gan-an Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìsìn Jèhófà (J. Kikot), July 
- “Mo Kẹ́kọ̀ọ́ Gan-an Lára Àwọn Míì!” (L. Breine), May 
- Mo Máa Ń Ro Ti Jèhófà Tí Mo Bá Ń Ṣèpinnu (D. Yazbek), June 
- Mò Ń Wá Bí Mo Ṣe Lè Gbé Ìgbé Ayé Tó Dáa (M. Witholt), Nov. 
- “Mo Ti Ń Gbádùn Iṣẹ́ Ìwàásù Báyìí!” (V. Vicini), Apr. 
Ọ̀KAN-Ò-JỌ̀KAN
- Arábìnrin Kan Rẹ́rìn-ín Músẹ́! Feb. 
- Kí ló ṣẹlẹ̀ sí ìlú Nínéfè lẹ́yìn ìgbà ayé Jónà? Nov. 
- Owó orí nígbà ayé Jésù, June 
- Wọ́n ń fi òrépèté ṣe ọkọ̀ ojú omi láyé ìgbà tí wọ́n ń kọ Bíbélì, May 
ILÉ ÌṢỌ́ TÁ À Ń FI SÓDE
- Ayé Tuntun Ti Dé Tán, No. 2 
- Kí Ló Lè Mú Kí Ọjọ́ Ọ̀la Rẹ Dáa? No. 3 
- Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Gbàdúrà? No. 1