Atọ́ka Àwọn Àkòrí Ilé Ìṣọ́ àti Jí! 2023
Ó ń tọ́ka sí ìwé ìròyìn tí àpilẹ̀kọ kọ̀ọ̀kan ti jáde
ILÉ ÌṢỌ́ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
ÀWA ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ
- Máa Fàánú Hàn sí Gbogbo Èèyàn, Dec. 
- 1923—Ní Ọgọ́rùn-ún Ọdún Sẹ́yìn, Oct. 
- Ọwọ́ Hulda Tẹ Ohun Tó Ń Wá, Nov. 
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
- “Arákùnrin Rẹ Máa Dìde”! Apr. 
- Àwọn Nǹkan Tó O Máa Ṣe Kó O Lè Ṣèrìbọmi, Mar. 
- Bá A Ṣe Lè Mú Kí Ìfẹ́ Tá A Ní Sáwọn Ará Túbọ̀ Lágbára, Nov. 
- Báwo La Ṣe Lè Jẹ́ Kí Ìgbàgbọ́ Wa Túbọ̀ Lágbára Pé Ayé Tuntun Máa Dé? Apr. 
- Báwo Ni Jèhófà Ṣe Ń Dáhùn Àdúrà Wa?, May 
- Bíi Ti Pétérù, Má Jẹ́ Kó Sú Ẹ, Sept. 
- Bó O Ṣe Lè Mọyì Ìwàláàyè Tí Ọlọ́run Fún Ẹ, Feb. 
- Bó O Ṣe Lè Mú Kí Àdúrà Ẹ Sunwọ̀n Sí I, May 
- Bó O Ṣe Lè Túbọ̀ Jàǹfààní Tó O Bá Ń Ka Bíbélì, Feb. 
- “Èyí Ni Gbogbo Èèyàn Máa Fi Mọ̀ Pé Ọmọ Ẹ̀yìn Mi Ni Yín,” Mar. 
- “Ẹ Dúró Gbọn-in, Ẹ Má Yẹsẹ̀,” July 
- Ẹ Máa Gba Ara Yín Níyànjú Nípàdé Ìjọ, Apr. 
- Ẹ Máa Múra Sílẹ̀ De Ọjọ́ Jèhófà, June 
- Ẹ Máa Ní Sùúrù, Aug. 
- “Ẹ Máa Ronú Bó Ṣe Tọ́, Ẹ Wà Lójúfò!” Feb. 
- “Ẹ Para Dà Nípa Yíyí Èrò Inú Yín Pa Dà,” Jan. 
- Ẹ̀yin Alàgbà, Ẹ Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Gídíónì, June 
- Ẹ̀yin Ọ̀dọ́, Báwo Lẹ Ṣe Fẹ́ Káyé Yín Rí? Sept. 
- Ẹ̀yin Ọ̀dọ́bìnrin, Ẹ Jẹ́ Kí Òtítọ́ Jinlẹ̀ Nínú Yín, Dec. 
- Ẹ̀yin Ọ̀dọ́kùnrin, Ẹ Jẹ́ Kí Òtítọ́ Jinlẹ̀ Nínú Yín, Dec. 
- Ẹ̀yin Tọkọtaya, Ẹ Jẹ́ Kí Ìfẹ́ Yín Dà Bí “Ọwọ́ Iná Jáà”, May 
- Gbé Ẹrù Tó Yẹ Kó O Gbé, Kó O sì Ju Èyí Tí Ò Yẹ Nù, Aug. 
- Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà Bíi Ti Sámúsìn, Sept. 
- “Ìfẹ́ Tí Kristi Ní Sọ Ọ́ Di Dandan fún Wa,” Jan. 
- Ìgbàgbọ́ àti Iṣẹ́ Máa Sọ Ẹ́ Di Olódodo, Dec. 
- Ìrètí Tó O Ní Ò Ní Já Ẹ Kulẹ̀, Dec. 
- Jèhófà Fi Dá Wa Lójú Pé Òun Máa Sọ Ayé Di Párádísè, Nov. 
- Jèhófà Máa Jẹ́ Kó O Ṣàṣeyọrí, Jan. 
- Jèhófà Máa Ń Bù Kún Wa Tá A Bá Ṣe Ìrántí Ikú Kristi, Jan. 
- Jèhófà Máa Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ Láti Fara Da Ìṣòro Tó Dé Bá Ẹ, Apr. 
- ‘Jèhófà Máa Sọ Ẹ́ Di Alágbára’ Oct. 
- Jẹ́ Kó Túbọ̀ Dá Ẹ Lójú Pé Jèhófà Máa Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ Nígbà Ìṣòro, Nov. 
- Jẹ́ Kó Túbọ̀ Dá Ẹ Lójú Pé Òtítọ́ Ni Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run, Jan. 
- Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Dáníẹ́lì, Aug. 
- Kẹ́kọ̀ọ́ Nínú Lẹ́tà Méjì Tí Pétérù Kọ, Sept. 
- Kí La Rí Kọ́ Nínú Àwọn Iṣẹ́ Ìyanu Tí Jésù Ṣe? Apr. 
- Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Bẹ̀rù Jèhófà? June 
- Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Ṣèrìbọmi? Mar. 
- Máa Fi Àwọn Nǹkan Tí Jèhófà Dá Kọ́ Ọmọ Rẹ, Mar. 
- Máa Fòye Báni Lò Bíi Ti Jèhófà, July 
- Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Jinlẹ̀, Oct. 
- Mọyì Àǹfààní Tó O Ní Láti Jọ́sìn Jèhófà Nínú Tẹ́ńpìlì Tẹ̀mí, Oct. 
- Ohun Tá A Rí Kọ́ Nínú Àsọtẹ́lẹ̀ Bíbélì, Aug. 
- Ohun Tí Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Sọ Nípa Ẹni Tó Ni Bíbélì, Feb. 
- “Ọ̀nà Ìjẹ́mímọ́” May 
- Ọwọ́ Ẹ Lè Tẹ Àwọn Àfojúsùn Ẹ, May 
- Ṣé Jèhófà Máa Dáhùn Àdúrà Mi? Nov. 
- Ṣé Ò Ń Múra Sílẹ̀ De Ìpọ́njú Ńlá? July 
- Ṣé O “Ṣe Tán Láti Ṣègbọràn”? Oct. 
- Tó O Bá Ní Ìwà Tútù, Wàá Di Alágbára, Sept. 
- Túbọ̀ Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Nípa Jèhófà Lára Àwọn Nǹkan Tó Dá, Mar. 
- Túbọ̀ Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà Àtàwọn Ará, July 
- Wàá Jàǹfààní Tó O Bá Ń Bẹ̀rù Ọlọ́run, June 
ÌBÉÈRÈ LÁTI ỌWỌ́ ÀWỌN ÒǸKÀWÉ
- Báwo ni àpilẹ̀kọ náà “Kí Orúkọ Rẹ Di Mímọ́” nínú Ilé Ìṣọ́ June 2020 ṣe ṣàlàyé ohun tá a gbà gbọ́ nípa orúkọ Jèhófà àti bó ṣe jẹ́ Ọba Aláṣẹ Ayé Àtọ̀run? Aug. 
- Kí nìdí tí Jósẹ́fù àti Màríà ò fi kúrò ní Bẹ́tílẹ́hẹ́mù? June 
- Kí nìdí tí ọkùnrin tí Bíbélì pè ní “Èèyàn mi” fi sọ pé òun máa “run” ogún òun tí òun bá fẹ́ Rúùtù? (Rúùtù 4:1, 6), Mar. 
- Ṣé mánà àti àparò nìkan làwọn ọmọ Ísírẹ́lì jẹ nígbà tí wọ́n wà ní aginjù? Oct. 
ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI ÀNÍMỌ́ KRISTẸNI
- Ṣé Ojú Tí Ọlọ́run Fi Ń Wo Ọtí Lo Fi Ń Wò Ó?, Dec. 
- Tí Ọkọ Tàbí Aya Kan Bá Ń Wo Àwòrán Ìṣekúṣe, Aug. 
- Wọ́n Fìfẹ́ Hàn sí Wọn Gan-an, Feb. 
ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ
- Jèhófà Dáàbò Bò Mí Torí Mo Gbẹ́kẹ̀ Lé E (I. Itajobi), Nov. 
- Mo Kẹ́kọ̀ọ́ Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìsìn Jèhófà, Ó sì Ṣe Ohun Tó Yà Mí Lẹ́nu (R. Kesk), June 
- Mo Ti Rí i Pé Jèhófà Ń Bù Kún Àwọn Ìránṣẹ́ Rẹ̀ Tó Nígbàgbọ́ (R. Landis), Feb. 
- Tá A Bá Ń Ran Àwọn Èèyàn Lọ́wọ́, A Máa Jàǹfààní Ẹ̀ Títí Láé (R. Reid), July 
ǸJẸ́ O MỌ̀?
- Báwo ni àwọn bíríkì tí wọ́n rí ní Bábílónì àtijọ́ tó ti di àwókù àti bí wọ́n ṣe ṣe bíríkì náà ṣe jẹ́rìí sí i pé àkọsílẹ̀ Bíbélì jóòótọ́? July 
OHUN TÓ O LÈ FI KẸ́KỌ̀Ọ́
- Àwọn Àpilẹ̀kọ Míì Nínú Ilé Ìṣọ́ (JW Library®), June 
- Àwọn Nǹkan Tá A Lè Fi Kọ́ Àwọn Ọmọdé (jw.org), Sept. 
- Àwọn Ohun Tá A Lè Fi Ṣèwádìí Lórí ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ™ ti Watchtower, May 
- Bá A Ṣe Lè Lo Abala “Ohun Tuntun” Lọ́nà Tó Dáa (JW Library® àti jw.org), Mar. 
- Báwo Lo Ṣe Lè Mọ Àwọn Òye Tuntun Tá A Ní (Watch Tower Publications Index tàbí Ìwé Ìwádìí fún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà), Oct. 
- Bó O Ṣe Lè Wá Àwọn Àpilẹ̀kọ Tó Máa Ń Wà Níbẹ̀rẹ̀ Jw.Org (jw.org), Feb. 
- Ìtàn ìgbésí ayé àwọn arákùnrin àtàwọn arábìnrin wa, Jan. 
- Máa jàǹfààní látinú àwọn ẹsẹ Bíbélì tá a ṣàlàyé nínú Ìwé Ìwádìí, Apr. 
- Mọ Àwọn Ohun Tó Yẹ Kó O Ṣe, July 
- Mọ “Àwọn Orin Ẹ̀mí” Sórí (jw.org), Nov. 
- Wá Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Nípa Jèhófà (Watch Tower Publications Index tàbí Ìwé Ìwádìí fún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà), Aug. 
ILÉ ÌṢỌ́ TÁ À Ń FI SÓDE
- Ohun Tí Bíbélì Sọ Nípa Ìlera Ọpọlọ, No. 1 
JÍ!
- Àwọn Èèyàn Ti Ba Ayé Yìí Jẹ́ Gan-an! Ṣé Ọ̀nà Àbáyọ Wà, No. 1