ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • ijwbq àpilẹ̀kọ 2
  • Ṣé Èrò Ọlọ́run Ló Wà Nínú Bíbélì?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ṣé Èrò Ọlọ́run Ló Wà Nínú Bíbélì?
  • Ohun Tí Bíbélì Sọ
  • Ìsọ̀rí
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ohun tí Bíbélì sọ
  • Kí Làwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Ìṣípayá Túmọ̀ Sí?
    Ohun Tí Bíbélì Sọ
  • Bí Ìṣípayá Ṣe Kàn Ọ́
    Ìṣípayá—Ìparí Rẹ̀ Ológo Kù sí Dẹ̀dẹ̀!
  • Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì Sọ Pé Àwọn Fẹ́ Ọba
    Kí Ló Wà Nínú Bíbélì?
  • Sámúẹ́lì Gbé Ìjọsìn Tòótọ́ Lárugẹ
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2007
Àwọn Míì
Ohun Tí Bíbélì Sọ
ijwbq àpilẹ̀kọ 2
Ẹnì kan ń kọ̀wé sínú àkájọ ìwé

Ṣé Èrò Ọlọ́run Ló Wà Nínú Bíbélì?

Ohun tí Bíbélì sọ

Ọ̀pọ̀ àwọn tó kọ Bíbélì sọ pé Ọlọ́run ló darí ohun táwọn kọ sílẹ̀. Wo àwọn àpẹẹrẹ yìí:

  • Dáfídì Ọba: “Ẹ̀mí Jèhófà ni ó sọ̀rọ̀ nípasẹ̀ mi, ọ̀rọ̀ rẹ̀ sì wà lórí ahọ́n mi.”—2 Sámúẹ́lì 23:1, 2.

  • Wòlíì Aísáyà: “Èyí ni ohun tí Olúwa Ọba Aláṣẹ, Jèhófà àwọn ẹ̀gbẹ́ ọmọ ogun, wí.”—Aísáyà 22:15.

  • Àpọ́sítélì Jòhánù: “Ìṣípayá láti ọ̀dọ̀ Jésù Kristi, èyí tí Ọlọ́run fi fún un.”—Ìṣípayá 1:1.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́