Bó O Ṣe Lè Wá Ẹsẹ Ìwé Mímọ́ Nínú Bíbélì Rẹ
 
 
Àwọn Ìwé Inú Bíbélìa
| Orúkọ Ìwé | Òǹkọ̀wé | Ìgbà Tí Wọ́n Kọ Ọ́ Tán | 
|---|---|---|
| Mósè | 1513 Ṣ.S.K. | |
| Mósè | 1512 Ṣ.S.K. | |
| Mósè | 1512 Ṣ.S.K. | |
| Mósè | 1473 Ṣ.S.K. | |
| Mósè | 1473 Ṣ.S.K. | |
| Jóṣúà | n. 1450 Ṣ.S.K. | |
| Sámúẹ́lì | n. 1100 Ṣ.S.K. | |
| Sámúẹ́lì | n. 1090 Ṣ.S.K. | |
| Sámúẹ́lì; Gádì; Nátánì | n. 1078 Ṣ.S.K. | |
| Gádì; Nátánì | n. 1040 Ṣ.S.K. | |
| Jeremáyà | 580 Ṣ.S.K. | |
| Jeremáyà | 580 Ṣ.S.K. | |
| Ẹ́sírà | n. 460 Ṣ.S.K. | |
| Ẹ́sírà | n. 460 Ṣ.S.K. | |
| Ẹ́sírà | n. 460 Ṣ.S.K. | |
| Nehemáyà | n. 443 Ṣ.S.K. | |
| Mọ́dékáì | n. 475 Ṣ.S.K. | |
| Mósè | n. 1473 Ṣ.S.K. | |
| Dáfídì àtàwọn míì | n. 460 Ṣ.S.K. | |
| Sólómọ́nì; Ágúrì; Lémúẹ́lì | n. 717 Ṣ.S.K. | |
| Sólómọ́nì | ṣ. 1000 Ṣ.S.K. | |
| Sólómọ́nì | n. 1020 Ṣ.S.K. | |
| Aísáyà | l. 732 Ṣ.S.K. | |
| Jeremáyà | 580 Ṣ.S.K. | |
| Jeremáyà | 607 Ṣ.S.K. | |
| Ìsíkíẹ́lì | n. 591 Ṣ.S.K. | |
| Dáníẹ́lì | n. 536 Ṣ.S.K. | |
| Hóséà | l. 745 Ṣ.S.K. | |
| Jóẹ́lì | n. 820 Ṣ.S.K. (?) | |
| Ámósì | n. 804 Ṣ.S.K. | |
| Ọbadáyà | n. 607 Ṣ.S.K. | |
| Jónà | n. 844 Ṣ.S.K. | |
| Míkà | ṣ. 717 Ṣ.S.K. | |
| Nahum | ṣ. 632 Ṣ.S.K. | |
| Hábákúkù | n. 628 Ṣ.S.K. (?) | |
| Sefanáyà | ṣ. 648 Ṣ.S.K. | |
| Hágáì | 520 Ṣ.S.K. | |
| Sekaráyà | 518 Ṣ.S.K. | |
| Málákì | l. 443 Ṣ.S.K. | |
| Mátíù | n. 41 S.K. | |
| Máàkù | n. 60-65 S.K. | |
| Lúùkù | n. 56-58 S.K. | |
| Àpọ́sítélì Jòhánù | n. 98 S.K. | |
| Lúùkù | n. 61 S.K. | |
| Pọ́ọ̀lù | n. 56 S.K. | |
| Pọ́ọ̀lù | n. 55 S.K. | |
| Pọ́ọ̀lù | n. 55 S.K. | |
| Pọ́ọ̀lù | n. 50-52 S.K. | |
| Pọ́ọ̀lù | n. 60-61 S.K. | |
| Pọ́ọ̀lùl | n. 60-61 S.K. | |
| Pọ́ọ̀lù | n. 60-61 S.K. | |
| Pọ́ọ̀lù | n. 50 S.K. | |
| Pọ́ọ̀lù | n. 51 S.K. | |
| Pọ́ọ̀lù | n. 61-64 S.K. | |
| Pọ́ọ̀lù | n. 65 S.K. | |
| Pọ́ọ̀lù | n. 61-64 S.K. | |
| Pọ́ọ̀lù | n. 60-61 S.K. | |
| Pọ́ọ̀lù | n. 61 S.K. | |
| Jémíìsì (Àbúrò Jésù) | ṣ. 62 S.K. | |
| Pétérù | n. 62-64 S.K. | |
| Pétérù | n. 64 S.K. | |
| Àpọ́sítélì Jòhánù | n. 98 S.K. | |
| Àpọ́sítélì Jòhánù | n. 98 S.K. | |
| Àpọ́sítélì Jòhánù | n. 98 S.K. | |
| Júúdà (àbúrò Jésù) | n. 65 S.K. | |
| Àpọ́sítélì Jòhánù | n. 96 S.K. | 
Àkíyèsí: Àwọn ìwé kan wà tí orúkọ àwọn tó kọ ọ́ àti ìgbà tí wọ́n kọ ọ́ tán ò dá wa lójú. Ṣe la fojú díwọ̀n ọ̀pọ̀ nínú àwọn déètì yìí, bí àpẹẹrẹ, àmì l. tó wà níwájú àwọn déètì kan túmọ̀ sí “lẹ́yìn,” ṣ. túmọ̀ sí “ṣáájú,” n. sì túmọ̀ sí “nǹkan bí.”
a Bá a ṣe to àwọn ìwé mẹ́rìndínláàádọ́rin (66) tó wà nínú Bíbélì síbí náà ni wọ́n ṣe tò ó tẹ̀ léra nínú ọ̀pọ̀ ìtumọ̀ Bíbélì. Ọgọ́rùn-ún ọdún kẹrin ni wọ́n ti bẹ̀rẹ̀ sí í tò ó lọ́nà yìí.