BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ
Mo Ti Wá Ní Èrò Tó Dáa Nípa Àwọn Èèyàn
Ọkùnrin yìí kẹ́kọ̀ọ́ òtítọ́ Bíbélì, ó fi ìgbé ayé oníjàgídíjàgan sílẹ̀, ó sì ń lọ káàkiri ọ̀dọ̀ àwọn èèyàn kó lè kọ́ wọn nípa ayé kan tí ò ní sí ìwà ọ̀daràn àtàwọn ọmọọ̀ta mọ́.