A7-B
Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Pàtàkì Nínú Ìgbésí Ayé Jésù—Ìbẹ̀rẹ̀ Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Jésù
| ÀKÓKÒ | IBI | ÌṢẸ̀LẸ̀ | MÁTÍÙ | MÁÀKÙ | LÚÙKÙ | JÒHÁNÙ | 
|---|---|---|---|---|---|---|
| 29, ìgbà ìwọ́wé | Odò Jọ́dánì, bóyá ní Bẹ́tánì tàbí nítòsí ibẹ̀, ní ìsọdá Jọ́dánì | Jésù ṣe ìrìbọmi, Ọlọ́run sì fi ẹ̀mí mímọ́ yàn án; Jèhófà sọ pé Ọmọ òun ni, ó sì tẹ́wọ́ gbà á | ||||
| Aginjù Jùdíà | Èṣù dán an wò | |||||
| Bẹ́tánì ní ìsọdá Jọ́dánì | Jòhánù Arinibọmi fi Jésù hàn pé ó jẹ́ Ọ̀dọ́ Àgùntàn Ọlọ́run; àwọn ọmọ ẹ̀yìn àkọ́kọ́ dara pọ̀ mọ́ Jésù | |||||
| Kánà ti Gálílì; Kápánáúmù | Iṣẹ́ ìyanu àkọ́kọ́ níbi ìgbéyàwó, ó sọ omi di wáìnì; ó lọ sí Kápánáúmù | |||||
| 30, Ìrékọjá | Jerúsálẹ́mù | Ó fọ tẹ́ńpìlì mọ́ | ||||
| Ó bá Nikodémù sọ̀rọ̀ | ||||||
| Jùdíà; Áínónì | Ó lọ sí ìgbèríko Jùdíà, àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ ń ṣèrìbọmi fún àwọn èèyàn; ẹ̀rí tí Jòhánù jẹ́ kẹ́yìn nípa Jésù | |||||
| Tìbéríà; Jùdíà | Wọ́n fi Jòhánù sẹ́wọ̀n; Jésù lọ sí Gálílì | |||||
| Síkárì, ní Samáríà | Nígbà tó ń lọ sí Gálílì, ó kọ́ àwọn ará Samáríà | 
Aginjù Jùdíà