A7-D
Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Pàtàkì Nínú Ìgbésí Ayé Jésù—Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Tó Ta Yọ Tí Jésù Ṣe ní Gálílì (Apá Kìíní)
| ÀKÓKÒ | IBI | ÌṢẸ̀LẸ̀ | MÁTÍÙ | MÁÀKÙ | LÚÙKÙ | JÒHÁNÙ | 
|---|---|---|---|---|---|---|
| 30 | Gálílì | Ìgbà àkọ́kọ́ tí Jésù kéde pé “Ìjọba ọ̀run ti sún mọ́lé” | ||||
| Kánà; Násárẹ́tì; Kápánáúmù | Ó mú ọmọ òṣìṣẹ́ ọba kan lára dá; ó ka àkájọ ìwé Àìsáyà; ó lọ sí Kápánáúmù | |||||
| Òkun Gálílì, nítòsí Kápánáúmù | Ó pe ọmọ ẹ̀yìn mẹ́rin: Símónì àti Áńdérù, Jémíìsì àti Jòhánù | |||||
| Kápánáúmù | Ó mú ìyá ìyàwó Símónì àtàwọn míì lára dá | |||||
| Gálílì | Ìrìn àjò àkọ́kọ́ ní Gálílì, pẹ̀lú ọmọ ẹ̀yìn mẹ́rin náà | |||||
| Ó wo adẹ́tẹ̀ sàn; àwọn èrò tẹ̀ lé e | ||||||
| Kápánáúmù | Ó wo alárùn rọpárọsẹ̀ kan sàn | |||||
| Ó pe Mátíù; ó bá àwọn agbowó orí jẹun; wọ́n béèrè ọ̀rọ̀ nípa ààwẹ̀ | ||||||
| Jùdíà | Ó wàásù nínú sínágọ́gù | |||||
| 31, Ìrékọjá | Jerúsálẹ́mù | Ó wo ọkùnrin aláìsàn tó wà ní Bẹtisátà sàn; Àwọn Júù ń wá bí wọ́n ṣe máa pa á | ||||
| Ó pa dà láti Jerúsálẹ́mù (?) | Àwọn ọmọ ẹ̀yìn ń ya erín ọkà jẹ lọ́jọ́ Sábáàtì; Jésù “Olúwa Sábáàtì” | |||||
| Gálílì; Òkun Gálílì | Ó mú ọkùnrin tí ọwọ́ rẹ̀ rọ lára dá lọ́jọ́ Sábáàtì; ọ̀pọ̀ èèyàn tẹ̀ lé e; ó wo ọ̀pọ̀ èèyàn sàn | |||||
| Òkè nítòsí Kápánáúmù | Ó yan àpọ́sítélì méjìlá | |||||
| Nítòsí Kápánáúmù | Ó ṣe Ìwàásù Lórí Òkè | |||||
| Kápánáúmù | Ó wo ìránṣẹ́ ọ̀gágun kan sàn | |||||
| Náínì | Ó jí ọmọ opó kan dìde | |||||
| Tìbéríà; Gálílì (Náínì tàbí nítòsí) | Jòhánù rán àwọn ọmọ ẹ̀yìn sí Jésù; a ṣí òtítọ́ payá fún àwọn ọmọdé; àjàgà rọrùn | |||||
| Gálílì (Náínì tàbí nítòsí) | Obìnrin ẹlẹ́ṣẹ̀ kan da òróró sí ẹsẹ̀ rẹ̀; àpèjúwe nípa àwọn ajigbèsè | |||||
| Gálílì | Ìrìn àjò kejì lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù, pẹ̀lú àwọn méjìlá (12) náà | |||||
| Ó lé àwọn ẹ̀mí èṣù jáde; ẹ̀ṣẹ̀ tí kò ní ìdáríjì | ||||||
| Àmì Jónà nìkan ló fún àwọn èèyàn | ||||||
| Ìyá rẹ̀ àtàwọn àbúrò rẹ̀ wá; ó sọ pé àwọn ọmọ ẹ̀yìn ni ẹbí òun |