B12-A
Ọ̀sẹ̀ Tí Jésù Lò Kẹ́yìn Kó Tó Kú (Apá Kìíní)
Jerúsálẹ́mù àti Agbègbè Rẹ̀
- Tẹ́ńpìlì 
- Ọgbà Gẹ́tísémánì (?) 
- Ààfin Gómìnà 
- Ilé Káyáfà (?) 
- Ààfin Tí Hẹ́rọ́dù Áńtípà Lò (?) 
- Adágún Omi Bẹtisátà 
- Adágún Omi Sílóámù 
- Gbọ̀ngàn Sàhẹ́ndìrìn (?) 
- Gọ́gọ́tà (?) 
- Ákélídámà (?) 
Lọ sí ọjọ́ tó o fẹ́: Nísàn 8 | Nísàn 9 | Nísàn 10 | Nísàn 11
Nísàn 8 (Sábáàtì)
ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀ (Ọjọ́ àwọn Júù máa ń bẹ̀rẹ̀ nígbà tí oòrùn bá wọ̀, ó sì máa ń parí sí ìgbà tí oòrùn bá wọ̀)
- Ó dé sí Bẹ́tánì lọ́jọ́ mẹ́fà ṣáájú ọjọ́ Ìrékọjá 
ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ
ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀
Nísàn 9
ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀
- Ó bá Símónì adẹ́tẹ̀ jẹun 
- Màríà da òróró náádì sí Jésù lórí 
- Àwọn Júù wá wo Jésù àti Lásárù 
ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ
- Ó wọ Jerúsálẹ́mù tiyì-tẹ̀yẹ 
- Ó kọ́ni ní tẹ́ńpìlì 
ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀
Nísàn 10
ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀
- Ó sun Bẹ́tánì mọ́jú 
ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ
- Ìrìn àjò ní kùtùkùtù sí Jerúsálẹ́mù 
- Ó fọ tẹ́ńpìlì mọ́ 
- Jèhófà sọ̀rọ̀ látọ̀run 
ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀
Nísàn 11
ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀
ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ
- Ó kọ́ni ní tẹ́ńpìlì, ó lo àpèjúwe 
- Ó dẹ́bi fún àwọn Farisí 
- Ó kíyè sí ọrẹ tí opó kan ṣe 
- Lórí Òkè Ólífì, ó sọ àsọtẹ́lẹ̀ ìparun Jerúsálẹ́mù àti àmì ìgbà tó máa wà níhìn-ín