B12-B
Ọ̀sẹ̀ Tí Jésù Lò Kẹ́yìn Kó Tó Kú (Apá Kejì)
Jerúsálẹ́mù àti Agbègbè Rẹ̀
- Tẹ́ńpìlì 
- Ọgbà Gẹ́tísémánì (?) 
- Ààfin Gómìnà 
- Ilé Káyáfà (?) 
- Ààfin Tí Hẹ́rọ́dù Áńtípà Lò (?) 
- Adágún Omi Bẹtisátà 
- Adágún Omi Sílóámù 
- Gbọ̀ngàn Sàhẹ́ndìrìn (?) 
- Gọ́gọ́tà (?) 
- Ákélídámà (?) 
Lọ sí ọjọ́ tó o fẹ́: Nísàn 12 | Nísàn 13 | Nísàn 14 | Nísàn 15 | Nísàn 16
Nísàn 12
ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀ (Ọjọ́ àwọn Júù máa ń bẹ̀rẹ̀ nígbà tí oòrùn bá wọ̀, ó sì máa ń parí sí ìgbà tí oòrùn bá wọ̀)
ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ
- Òun àtàwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ jọ wà níbi tó pa rọ́rọ́ 
- Júdásì ṣètò bí wọ́n ṣe máa mú Jésù 
ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀
Nísàn 13
ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀
ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ
- Pétérù àti Jòhánù múra sílẹ̀ fún Ìrékọjá 
- Jésù àtàwọn àpọ́sítélì yòókù dé ní ọjọ́rọ̀ 
ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀
Nísàn 14
ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀
- Òun àtàwọn àpọ́sítélì rẹ̀ jẹ Ìrékọjá 
- Ó fọ ẹsẹ̀ àwọn àpọ́sítélì 
- Ó ní kí Júdásì máa lọ 
- Ó dá Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa sílẹ̀ 
Nísàn 15 (Sábáàtì)
ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀
ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ
- Pílátù gbà pé kí wọ́n fi àwọn ẹ̀ṣọ́ ṣọ́ sàréè Jésù 
ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀
Nísàn 16
ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ
- Ó jíǹde 
- Ó fara han àwọn ọmọ ẹ̀yìn