Wá Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Yìí:
- Kí ni “òfin Kristi”? (Gál. 6:2) 
- Báwo la ṣe lè mú òfin Kristi ṣẹ nígbà tá a bá dá wà? (1 Kọ́r. 10:31) 
- Báwo la ṣe lè mú òfin Kristi ṣẹ lẹ́nu iṣẹ́ òjíṣẹ́ wa? (Lúùkù 16:10; Mát. 22:39; Ìṣe 20:35) 
- Kí ló mú kí òfin Kristi ju Òfin Mósè lọ? (1 Pét. 2:16) 
- Báwo làwọn tọkọtaya àtàwọn òbí ṣe lè mú òfin Kristi ṣẹ nínú ìdílé wọn? (Éfé. 5:22, 23, 25; Héb. 5:13, 14) 
- Báwo lo ṣe lè mú òfin Kristi ṣẹ ní iléèwé? (Sm. 1:1-3; Jòh. 17:14) 
- Báwo la ṣe lè nífẹ̀ẹ́ àwọn èèyàn bí Jésù ṣe nífẹ̀ẹ́ wa? (Gál. 6:1-5, 10)