Má Sọ̀rètí Nù Bó O Ṣe Ń Mú Òfin Kristi Ṣẹ!
ÒWÚRỌ̀
- 9:40 [11:30]a Ohùn Orin 
- 9:50 [11:40] Orin 17 àti Àdúrà 
- 10:00 [11:50] Kí Ni Òfin Kristi? 
- 10:15 [12:05] Bá A Ṣe Lè Mú Òfin Kristi Ṣẹ Nígbà Tá A Bá Dá Wà 
- 10:30 [12:20] Bá A Ṣe Lè Mú Òfin Kristi Ṣẹ Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìwàásù 
- 10:55 [12:45] Orin 70 àti Ìfilọ̀ 
- 11:05 [12:55] Kí Nìdí Tí Òfin Kristi Fi Ju Òfin Mósè Lọ? 
- 11:35 [1:25] Ìyàsímímọ́ àti Ìrìbọmi 
- 12:05 [1:55] Orin 51 
Ọ̀SÁN
- 1:20 [2:35] Ohùn Orin 
- 1:30 [2:45] Orin 76 
- 1:35 [2:50] Ìrírí 
- 1:45 [3:00] Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́ 
- 2:15 [3:30] Bá A Ṣe Lè Mú Òfin Kristi Ṣẹ Nínú Ìdílé 
- 2:30 [3:45] Bá A Ṣe Lè Mú Òfin Kristi Ṣẹ ní Iléèwé 
- 2:45 [4:00] Orin 35 àti Ìfilọ̀ 
- 2:55 [4:10] Ẹ Nífẹ̀ẹ́ Ara Yín Bí Jésù Ṣe Nífẹ̀ẹ́ Yín 
- 3:55 [5:10] Orin 13 àti Àdúrà 
a Àkókò tó wà nínú àkámọ́ [ ] ni a ó tẹ̀ lé ní Sátidé tó bá jẹ́ ọjọ́ “Gbálùúmọ́”