Mú Ọkàn Jèhófà Yọ̀!
ÒWÚRỌ̀
- 9:30 Ohùn Orin 
- 9:40 Orin 29 àti Àdúrà 
- 9:50 Mú Ọkàn Jèhófà Yọ̀! 
- 10:05 Àpínsọ Àsọyé: Fìwà Jọ Jèhófà Láwọn Ọ̀nà Pàtàkì Yìí - • Ó Jẹ́ Onídàájọ́ Òdodo 
- • Ó Jẹ́ Alágbára 
- • Ó Jẹ́ Ọlọ́gbọ́n 
- • Ó Jẹ́ Onífẹ̀ẹ́ 
 
- 11:05 Orin 81 àti Ìfilọ̀ 
- 11:15 Máa “So Èso Púpọ̀” Kó O Lè Fògo fún Ọlọ́run 
- 11:30 Ìyàsímímọ́ àti Ìrìbọmi 
- 12:00 Orin 49 
Ọ̀SÁN
- 1:10 Ohùn Orin 
- 1:20 Orin 28 àti Àdúrà 
- 1:30 Àsọyé fún Gbogbo Èèyàn: Bí O Ṣe Lè Mú Ọkàn Ọlọ́run Yọ̀ 
- 2:00 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́ 
- 2:30 Orin 35 àti Ìfilọ̀ 
- 2:40 Àpínsọ Àsọyé: Máa Ṣe Ohun Tí Inú Jèhófà Dùn Sí . . . - • Ní Ìgbésí Ayé Rẹ 
- • Nínú Ìdílé Rẹ 
- • Nínú Ìjọ Rẹ 
- • Ní Àdúgbò Rẹ 
 
- 3:40 “Ìdùnnú Jèhófà Ni Agbára Yín” 
- 4:15 Orin 110 àti Àdúrà