ORIN 160
“Ìhìn Rere”!
Bíi Ti Orí Ìwé
	- 1. Ìròyìn ayọ̀ ti dé. - Ògo f’Ọlọ́run. - A bí Olùgbàlà kan fún wa. - Òmìnira dé. - A ti wá nírètí! - (ÈGBÈ) - Ìròyìn ayọ̀! - Wàásù rẹ̀ fáyé. - Ẹ yin Jèhófà! - Ó tan ìmọ́lẹ̀ - òtítọ́ fún wa. - Wàásù pé Jésù - Lọ̀nà, òótọ́, ìyè. 
- 2. Yóò mú kí àlàáfíà wà - Ní gbogbo ayé. - Ipasẹ̀ rẹ̀ la máa fi ríyè. - Ìjọba Jésù - Máa dúró títí láé. - (ÈGBÈ) - Ìròyìn ayọ̀! - Wàásù rẹ̀ fáyé. - Ẹ yin Jèhófà! - Ó tan ìmọ́lẹ̀ - òtítọ́ fún wa. - Wàásù pé Jésù - Lọ̀nà, òótọ́, ìyè. - (ÈGBÈ) - Ìròyìn ayọ̀! - Wàásù rẹ̀ fáyé. - Ẹ yin Jèhófà! - Ó tan ìmọ́lẹ̀ - òtítọ́ fún wa. - Wàásù pé Jésù - Lọ̀nà, òótọ́, ìyè. 
(Tún wo Mát. 24:14; Jòh. 8:12; 14:6; Àìsá. 32:1; 61:2.)