Má Ṣe Jẹ́ Kí Ìhìn Rere Tì Ẹ́ Lójú
Àárọ̀
- 9:40 Ohùn Orin 
- 9:50 Orin 67 àti Àdúrà 
- 10:00 Kí Nìdí Tí ‘Ìhìn Rere Ò Fi Tì Wá lójú?’ 
- 10:15 Máa Fìgboyà Sọ Ohun Tó O Gbà Gbọ́ 
- 10:30 Jẹ́ “Òṣìṣẹ́ Tí Kò Ní Ohunkóhun Tó Máa Tì Í Lójú” 
- 10:55 Orin 73 àti Ìfilọ̀ 
- 11:05 Bá A Ṣe Lè Fi Hàn Pé A Ní Ẹ̀mí Agbára, Ìfẹ́ àti Àròjinlẹ̀ 
- 11:35 Ìrìbọmi: Máa “Ṣègbọràn sí Ìhìn Rere” 
- 12:05 Orin 75