ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌSÍKÍẸ́LÌ 35-38
Gọ́ọ̀gù Ti Ilẹ̀ Mágọ́gù Máa Tó Pa Run
Bíbélì ṣàlàyé àwọn nǹkan tó máa ṣẹlẹ̀ kí Gọ́ọ̀gù ti ilẹ̀ Mágọ́gù tó pa run àti lẹ́yìn tó bá pa run.
- Ìparun kí ló máa bẹ̀rẹ̀ ìpọ́njú ńlá? 
- Ta ló máa gbéjà ko àwa èèyàn Jèhófà? 
- Ogun wo ni Jèhófà máa fi pa Gọ́ọ̀gù ti ilẹ̀ Mágọ́gù run? 
- Ọdún mélòó ni Kristi fi máa ṣàkóso? 
Báwo ni mo ṣe lè múra sílẹ̀ nípa tẹ̀mí de ìgbà tí Gọ́ọ̀gù ti ilẹ̀ Mágọ́gù máa gbéjà ko àwa èèyàn Jèhófà?