ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | MÁTÍÙ 16-17
Èrò Ta Ni Ò Ń Rò?
- Bó tiẹ̀ jẹ́ pé ohun tó dáa ló wà lọ́kàn Pétérù, Jésù tètè tún èrò òdí tí Pétérù ní ṣe 
- Jésù mọ̀ pé àkókò yẹn kọ́ ló yẹ kí òun “ṣàánú” ara òun. Ohun tí Sátánì fẹ́ gan-an ni pé kí Jésù dẹwọ́ ní àkókò pàtàkì yẹn 
Jésù jẹ́ ká mọ ohun mẹ́ta tó yẹ ká ṣe tá a bá fẹ́ ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run délẹ̀délẹ̀. Kí ni ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn túmọ̀ sí?
- Sẹ́ ara rẹ 
- Gbé òpó igi oró rẹ 
- Máa tọ Kristi lẹ́yìn