January 15 Ogun Ha Jẹ́ Aláìṣeéyẹ̀sílẹ̀ Bí? Láìpẹ́—Ayé kan Láìsí Ogun! Àwọn Ẹlẹ́rìí Jehofa Káàkiri Ayé—Ìlú Aláààrẹ Ti Philippines Jehofa Ń Ṣàkóso—Nípasẹ̀ Ìṣàkóso Ọlọrun Àwọn Olùṣọ́-Àgùtàn Àti Àwọn Àgùtàn Nínú Ìṣàkóso Ọlọrun Àwọn Aṣáájú-Ọ̀nà Ń Fìbùkún Jíǹkí Ẹni Wọ́n Sì Ń Rí I Gbà Àwọn Àpéjọpọ̀ Tí Ń Rùmọ̀lárasókè Gbé Ẹ̀kọ́ Àtọ̀runwá Ga Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé Ẹsẹ Ìwé Mímọ́ Ojoojúmọ́ Fún Ọdún 1994