Koko Ẹ̀kọ́ Inu Iwe
4 O Lóyún Ṣugbọn Kò Ṣe Igbeyawo
9 Ibẹrẹpẹpẹ Igbesi-aye Idile Jesu
10 Awọn Irin Ajo si Jerusalẹmu
13 Kikẹkọọ Lati Inu Awọn Ìdẹwò Jesu
18 Johanu Ńpẹ̀dín, Jesu Nbisii
19 Kíkọ́ Obinrin Ara Samaria Kan Lẹkọọ
21 Ninu Sinagọgu Ilu Ibilẹ Jesu
23 Iṣẹ Iyanu Pupọ Sii ni Kapanaomu
26 Lẹhin Dídé Ilé ní Kapanaomu
29 Ṣíṣe Awọn Iṣẹ́ Rere ní Sabaati
30 Dídá Awọn Olùfisùn Rẹ̀ Lóhùn
32 Ki Ni Ohun Tí Ó Bófinmu ní Sabaati?
35 Ìwàásù Tí O Lókìkí Julọ Tí A Tíì Fúnni Rí
36 Ìgbàgbọ́ Títóbi Ọ̀gágun Kan
37 Jesu Lé Ẹ̀dùn Ọkàn Ọpó Kan Lọ
38 Johanu Ha Ṣàìní Ìgbàgbọ́ Bí?
39 Awọn Agbéraga ati Awọn Onirẹlẹ
40 Ẹ̀kọ́ Àríkọ́gbọ́n Kan Nipa Àánú
41 Ẹni Ti Àríyànjiyàn Dale Lori
42 Jesu Bá Awọn Farisi Wi Lọna Lilekoko
43 Kíkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Pẹlu Awọn Àkàwé
44 Mímú Ìjì Apaniláyà Kan Dákẹ́
45 Ọmọ-ẹhin Kan Tí A Kò Ronúkàn
46 Obinrin Naa Fọwọ́kàn Ẹ̀wù Rẹ̀
48 Fífi Ilé Jairu Silẹ ati Pípadà Ṣèbẹ̀wò Sí Nasarẹti
49 Ìrìn Àjò Iwaasu Miiran ní Galili
50 Ìmúrasílẹ̀ Lati Dojúkọ Inúnibíni
51 Ìṣìkàpànìyàn Nigba Àpèjẹ Ọjọ́-ìbí Kan
52 Jesu Bọ́ Ẹgbẹẹgbẹrun Lọna Iṣẹ́-ìyanu
53 Olùṣàkóso Ti O Ju Ẹda Eniyan Lọ Kan Tí A Nífẹ̀ẹ́ Sí
55 Ọ̀pọ̀ Ọmọ-ẹhin Pada Lẹhin Jesu
56 Ki Ni Ńsọ Ènìyàn di Ẹlẹ́gbin?
57 Ìyọ́nú fun Awọn Ti A Npọnloju
58 Awọn Ìṣù Burẹdi ati Ìwúkàrà
60 Ifihan Ṣaaju Ògo Ijọba Kristi
61 A Mú Ọmọdekunrin Tí O Ni Ẹ̀mí Buruku Láradá
62 Ẹ̀kọ́ Àríkọ́gbón Kan Nipa Ìrẹ̀lẹ̀
63 Ìmọ̀ràn Atọ́nisọ́nà Siwaju Síi
64 Ẹ̀kọ́ Àríkọ́gbọ́n Kan Nipa Ìdáríjì
65 Ìrìn Àjò Bòókẹ́lẹ́ Kan sí Jerusalemu
66 Ní Àjọ-àríyá Awọn Àgọ́-ìsìn
67 Wọn Kùnà Lati Fi Àṣẹ Ọba Mú Un
68 Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Siwaju Síi ní Ọjọ́ Keje
69 Àríyànjiyàn Lori Ipò Jijẹ Baba
70 Mímú Ọkunrin Kan Tí A Bí Ní Afọ́jú Láradá
71 Awọn Farisi Mọ̀ọ́mọ̀ Ṣaigbagbọ
73 Ará Samaria Aládùúgbò Rere Kan
74 Ìmọ̀ràn fun Mata, ati Ìtọ́ni Lórí Adura
79 Orílẹ̀-èdè Kan Sọnù, Ṣugbọn Kii Ṣe Gbogbo Rẹ̀
80 Awọn Ọgbà-àgùntàn ati Olùṣọ́-àgùtàn
81 Ìgbìdánwò Siwaju Sii Lati Pa Jesu
82 Jesu Lẹẹkan Sii Forile Jerusalẹmu
87 Pèsè fun Ọjọ́ Ọ̀la Pẹlu Ọgbọ́n Ti O Ṣeemulo
88 Ọkunrin Ọlọ́rọ̀ Naa ati Lasaru
89 Iṣẹ́-àpèrán Aláàánú Kan Sí Judia
92 A Mú Awọn Adẹ́tẹ̀ Mẹ́wàá Láradá Lákòókò Ìrìn Àjò Jesu Tí Ó Kẹhin sí Jerusalẹmu
93 Nigba Ti A Bá Ṣí Ọmọkunrin Ènìyàn Payá
94 Ìdí fun Adura ati fun Ìrẹ̀lẹ̀
95 Awọn Ẹ̀kọ́ Àríkọ́gbọ́n Lórí Ìkọ̀sílẹ̀ ati Lórí Ìfẹ́ fun Awọn Ọmọ
96 Jesu ati Ọ̀dọ́ Olùṣàkóso Kan Ti O Lọ́rọ̀
97 Awọn Òṣìṣẹ́ Ninu Ọgbà Àjàrà
98 Awọn Ọmọ-ẹhin Ńjiyàn bí Ikú Jesu ti Ńsúnmọ́lé
99 Jesu Kọ́nilẹ́kọ̀ọ́ ní Jẹriko
102 Kristi Wọ Jerusalẹmu Pẹlu Ayọ̀ Ìṣẹ́gun
103 Bíbẹ Tẹmpili Wò Lẹẹkan Sii
104 A Gbọ́ Ohùn Ọlọrun Ní Ìgbà Kẹta
105 Ìbẹ̀rẹ̀ Ọjọ́ Tí Ó Ṣekókó Naa
106 Awọn Àkàwé Ọgbà Àjàrà Tú Wọn Fó
108 Wọn Kùnà Lati Dẹkùn Mú Jesu
109 Jesu Fi Awọn Alátakò Rẹ̀ Bú
110 Iṣẹ́-òjíṣẹ́ ní Tẹmpili Parí
112 Ìrékọjá Ìgbẹ̀hìn Fun Jesu Kù Sí Dẹ̀dẹ̀
113 Ìrẹ̀lẹ̀ Lakooko Ìrékọjá Ikẹhin
116 Mimura Awọn Apọsiteli Silẹ fun Igberalọ Rẹ̀
118 Ìtáṣìrí ati Ìfàṣẹ Ọba Muni
119 A Mú Un Lọ Sọdọ Anasi, Lẹhin Naa Sọdọ Kaifa
121 Niwaju Sanhẹdrin, Lẹhin Naa Sọdọ Pilatu
122 Lati Ọ̀dọ̀ Pilatu Sọdọ Hẹrọdu A sì Tún Rán an Pada
124 A Fà Á lé Wọn Lọwọ Wọn Si Mu Un Lọ
126 “Dajudaju Ọmọkunrin Ọlọrun Ni Eyi”
127 A Sin ín ni Friday—Iboji Rẹ̀ Ṣofo ni Sunday
131 Awọn Ifarahan Ikẹhin, ati Pentikọsi 33 C.E.
133 Jesu Pari Gbogbo Ohun Ti Ọlọrun Beere Fun