ORIN 120
Jẹ́ Oníwà Tútù Bíi Kristi
Bíi Ti Orí Ìwé
	- 1. Jésù lẹni tó tóbi jù lọ láyé. - Ìgbéraga kò sí nínú ìwà rẹ̀. - Ipò ńlá ni Jèhófà fi Jésù sí. - Síbẹ̀, onírẹ̀lẹ̀ ni látọkàn wá. 
- 2. Gbogbo àwọn tó ní ìdààmú ọkàn, 
- 3. Jésù sọ pé ará ni gbogbo wa jẹ́. - Òun ni Orí wa, àṣẹ rẹ̀ là ń tẹ̀ lé. 
Jésù ṣe tán láti bá wọn gbẹ́rù wọn.
Àwọn oníwà tútù yóò rítura
Bí wọ́n ṣe ń wá ire Ìjọba ọ̀run.
Ọlọ́run mọyì àwọn onírẹ̀lẹ̀.
Ó ṣèlérí pé wọ́n máa jogún ayé.
(Tún wo Òwe 3:34; Mát. 5:5; 23:8; Róòmù 12:16.)