1 TÍMÓTÌ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
-  1  - 
- Ìkíni (1, 2) 
- Ìkìlọ̀ torí àwọn olùkọ́ èké (3-11) 
- Inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí tí a fi hàn sí Pọ́ọ̀lù (12-16) 
- Ọba ayérayé (17) 
- ‘Máa ja ogun rere’ (18-20) 
 
-  2  
-  3  - 
- Ohun tí alábòójútó gbọ́dọ̀ dójú ìlà rẹ̀ (1-7) 
- Ohun tí ìránṣẹ́ iṣẹ́ òjíṣẹ́ gbọ́dọ̀ dójú ìlà rẹ̀ (8-13) 
- Àṣírí mímọ́ ti ìfọkànsin Ọlọ́run (14-16) 
 
-  4  - 
- Ẹ máa ṣọ́ra torí ẹ̀kọ́ àwọn ẹ̀mí èṣù (1-5) 
- Bí o ṣe lè jẹ́ òjíṣẹ́ rere fún Kristi (6-10) 
- Máa kíyè sí ẹ̀kọ́ rẹ (11-16) 
 
-  5  - 
- Bí o ṣe máa hùwà sí àwọn ọ̀dọ́ àtàwọn àgbà (1, 2) 
- Máa ran àwọn opó lọ́wọ́ (3-16) 
- Bọlá fún àwọn alàgbà tó ń ṣiṣẹ́ kára (17-25) 
 
-  6  - 
- Kí àwọn ẹrú máa bọlá fún ọ̀gá wọn (1, 2) 
- Àwọn olùkọ́ èké àti ìfẹ́ owó (3-10) 
- Àwọn ìtọ́ni fún èèyàn Ọlọ́run (11-16) 
- Máa ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ iṣẹ́ rere (17-19) 
- Máa ṣọ́ ohun tí a fi sí ìkáwọ́ rẹ (20, 21)