2 TÍMÓTÌ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
-  1  - 
- Ìkíni (1, 2) 
- Pọ́ọ̀lù dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run torí ìgbàgbọ́ Tímótì (3-5) 
- Jẹ́ kí ẹ̀bùn Ọlọ́run máa jó bí iná (6-11) 
- Máa tẹ̀ lé àwọn ọ̀rọ̀ tó ṣàǹfààní (12-14) 
- Àwọn ọ̀tá Pọ́ọ̀lù àtàwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ (15-18) 
 
-  2  - 
- Fi ọ̀rọ̀ náà síkàáwọ́ àwọn ọkùnrin tó kúnjú ìwọ̀n (1-7) 
- Jìyà nítorí ìhìn rere (8-13) 
- Máa lo ọ̀rọ̀ Ọlọ́run bó ṣe yẹ (14-19) 
- Sá fún àwọn ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ìgbà ọ̀dọ́ (20-22) 
- Ohun tí o lè ṣe sí àwọn alátakò (23-26) 
 
-  3  - 
- Nǹkan máa le gan-an ní àwọn ọjọ́ ìkẹyìn (1-7) 
- Tẹ̀ lé àpẹẹrẹ Pọ́ọ̀lù pẹ́kípẹ́kí (8-13) 
- “Má ṣe fi àwọn nǹkan tí o ti kọ́ sílẹ̀” (14-17) 
 
-  4  - 
- “Ṣe iṣẹ́ òjíṣẹ́ rẹ láìkù síbì kan” (1-5) 
- “Mo ti ja ìjà rere náà” (6-8) 
- Àwọn ọ̀rọ̀ ara ẹni (9-18) 
- Ìkíni tó fi parí ọ̀rọ̀ rẹ̀ (19-22)