2 SÁMÚẸ́LÌ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
-  1  
-  2  
-  3  - 
- Ilé Dáfídì ń di alágbára sí i (1) 
- Àwọn ọmọkùnrin Dáfídì (2-5) 
- Ábínérì lọ dara pọ̀ mọ́ Dáfídì (6-21) 
- Jóábù pa Ábínérì (22-30) 
- Dáfídì ṣọ̀fọ̀ Ábínérì (31-39) 
 
-  4  
-  5  - 
- Dáfídì di ọba lórí gbogbo Ísírẹ́lì (1-5) 
- Wọ́n gba Jerúsálẹ́mù (6-16) 
- Dáfídì ṣẹ́gun àwọn Filísínì (17-25) 
 
-  6  
-  7  - 
- Dáfídì kò ní lè kọ́ tẹ́ńpìlì (1-7) 
- Ọlọ́run bá Dáfídì dá májẹ̀mú ìjọba (8-17) 
- Àdúrà ìdúpẹ́ tí Dáfídì gbà (18-29) 
 
-  8  
-  9  
- 10  
- 11  - 
- Dáfídì àti Bátí-ṣébà ṣe àgbèrè (1-13) 
- Dáfídì ṣètò pé kí wọ́n pa Ùráyà (14-25) 
- Dáfídì fi Bátí-ṣébà ṣe aya (26, 27) 
 
- 12  - 
- Nátánì bá Dáfídì wí (1-15a) 
- Ọmọ Bátí-ṣébà kú (15b-23) 
- Bátí-ṣébà bí Sólómọ́nì (24, 25) 
- Dáfídì gba ìlú Rábà tó jẹ́ ti àwọn ọmọ Ámónì (26-31) 
 
- 13  - 
- Ámínónì fipá bá Támárì lò pọ̀ (1-22) 
- Ábúsálómù pa Ámínónì (23-33) 
- Ábúsálómù sá lọ sí Géṣúrì (34-39) 
 
- 14  - 
- Jóábù àti obìnrin ará Tèkóà (1-17) 
- Dáfídì já ọgbọ́nkọ́gbọ́n Jóábù (18-20) 
- Dáfídì gbà kí Ábúsálómù pa dà (21-33) 
 
- 15  - 
- Ọ̀tẹ̀ àti rìkíṣí tí Ábúsálómù dì (1-12) 
- Dáfídì sá kúrò ní Jerúsálẹ́mù (13-30) 
- Áhítófẹ́lì dara pọ̀ mọ́ Ábúsálómù (31) 
- Ọba rán Húṣáì láti ta ko Áhítófẹ́lì (32-37) 
 
- 16  - 
- Síbà sọ̀rọ̀ Méfíbóṣétì láìdáa (1-4) 
- Ṣíméì gbé Dáfídì ṣépè (5-14) 
- Ábúsálómù gba Húṣáì sọ́dọ̀ (15-19) 
- Ìmọ̀ràn Áhítófẹ́lì (20-23) 
 
- 17  
- 18  
- 19  - 
- Dáfídì ṣọ̀fọ̀ Ábúsálómù (1-4) 
- Jóábù bá Dáfídì wí (5-8a) 
- Dáfídì pa dà sí Jerúsálẹ́mù (8b-15) 
- Ṣíméì tọrọ ìdáríjì (16-23) 
- Méfíbóṣétì fi hàn pé òun ò ṣẹ̀ (24-30) 
- Básíláì gbayì (31-40) 
- Àríyànjiyàn láàárín àwọn ẹ̀yà Ísírẹ́lì (41-43) 
 
- 20  
- 21  
- 22  
- 23  
- 24