ÌSÍKÍẸ́LÌ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
-  1  - 
- Ìsíkíẹ́lì wà ní Bábílónì, ó ń rí ìran látọ̀dọ̀ Ọlọ́run (1-3) 
- Ìran kẹ̀kẹ́ ẹṣin Jèhófà tó wà lọ́run (4-28) - 
- Ìjì líle, ìkùukùu àti iná (4) 
- Ẹ̀dá alààyè mẹ́rin (5-14) 
- Àgbá kẹ̀kẹ́ mẹ́rin (15-21) 
- Ohun kan tó tẹ́ pẹrẹsẹ, tó ń tàn yinrin bíi yìnyín (22-24) 
- Ìtẹ́ Jèhófà (25-28) 
 
 
-  2  
-  3  
-  4  
-  5  
-  6  
-  7  
-  8  
-  9  
- 10  - 
- Wọ́n mú iná láàárín àwọn àgbá kẹ̀kẹ́ náà (1-8) 
- Bí àwọn kérúbù àti àgbá kẹ̀kẹ́ náà ṣe rí (9-17) 
- Ògo Ọlọ́run kúrò ní tẹ́ńpìlì náà (18-22) 
 
- 11  - 
- Ọlọ́run dá àwọn ìjòyè burúkú lẹ́jọ́ (1-13) 
- Ọlọ́run ṣèlérí pé wọ́n á pa dà sílé (14-21) 
- Ògo Ọlọ́run kúrò ní Jerúsálẹ́mù (22, 23) 
- Ìsíkíẹ́lì pa dà sí Kálídíà nínú ìran (24, 25) 
 
- 12  
- 13  
- 14  
- 15  
- 16  
- 17  
- 18  
- 19  
- 20  - 
- Ìtàn nípa bí Ísírẹ́lì ṣe ṣọ̀tẹ̀ (1-32) 
- Ọlọ́run ṣèlérí pé òun yóò dá Ísírẹ́lì pa dà sórí ilẹ̀ wọn (33-44) 
- Sọ tẹ́lẹ̀ nípa gúúsù (45-49) 
 
- 21  - 
- Ọlọ́run fa idà tó fẹ́ fi ṣèdájọ́ yọ nínú àkọ̀ (1-17) 
- Ọba Bábílónì máa gbéjà ko Jerúsálẹ́mù (18-24) 
- Ọlọ́run máa mú ìjòyè burúkú Ísírẹ́lì kúrò (25-27) 
- Idà yóò bá àwọn ọmọ Ámónì jà (28-32) 
 
- 22  - 
- Jerúsálẹ́mù, ìlú tó jẹ̀bi ẹ̀jẹ̀ (1-16) 
- Ísírẹ́lì dà bí ìdàrọ́ tí kò wúlò (17-22) 
- Ọlọ́run bá àwọn aṣáájú àti àwọn èèyàn Ísírẹ́lì wí (23-31) 
 
- 23  
- 24  
- 25  - 
- Sọ àsọtẹ́lẹ̀ sórí Ámónì (1-7) 
- Sọ àsọtẹ́lẹ̀ sórí Móábù (8-11) 
- Sọ àsọtẹ́lẹ̀ sórí Édómù (12-14) 
- Sọ àsọtẹ́lẹ̀ sórí Filísíà (15-17) 
 
- 26  
- 27  
- 28  - 
- Ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sí ọba Tírè (1-10) 
- Orin arò nípa ọba Tírè (11-19) 
- Sọ àsọtẹ́lẹ̀ sórí Sídónì (20-24) 
- Ọlọ́run yóò tún kó Ísírẹ́lì jọ (25, 26) 
 
- 29  
- 30  
- 31  
- 32  
- 33  - 
- Iṣẹ́ olùṣọ́ (1-20) 
- Ìròyìn ìparun Jerúsálẹ́mù (21, 22) 
- Ọlọ́run rán ẹnì kan sí àwọn tó ń gbé inú àwókù (23-29) 
- Àwọn èèyàn ò ṣe ohun tí wọ́n gbọ́ (30-33) 
 
- 34  
- 35  
- 36  
- 37  
- 38  
- 39  - 
- Gọ́ọ̀gù àti àwọn ọmọ ogun rẹ̀ yóò pa run (1-10) 
- Wọ́n á sìnkú sí Àfonífojì Hamoni-Gọ́ọ̀gù (11-20) 
- Ọlọ́run yóò pa dà kó Ísírẹ́lì jọ (21-29) 
 
- 40  - 
- Ọlọ́run mú Ìsíkíẹ́lì wá sí Ísírẹ́lì nínú ìran (1, 2) 
- Ìsíkíẹ́lì rí tẹ́ńpìlì nínú ìran (3, 4) 
- Àwọn àgbàlá àti àwọn ẹnubodè (5-47) - 
- Ẹnubodè ìlà oòrùn tó wà níta (6-16) 
- Àgbàlá ìta; àwọn ẹnubodè míì (17-26) 
- Àgbàlá inú àti àwọn ẹnubodè (27-37) 
- Àwọn yàrá tí wọ́n ń lò fún iṣẹ́ tẹ́ńpìlì (38-46) 
- Pẹpẹ (47) 
 
- Ibi àbáwọlé tẹ́ńpìlì (48, 49) 
 
- 41  - 
- Ibi mímọ́ tẹ́ńpìlì (1-4) 
- Ògiri àti àwọn yàrá ẹ̀gbẹ́ (5-11) 
- Ilé tó wà ní ìwọ̀ oòrùn (12) 
- Ó wọn àwọn ilé náà (13-15a) 
- Inú ibi mímọ́ (15b-26) 
 
- 42  
- 43  
- 44  - 
- Ẹnubodè ìlà oòrùn yóò wà ní títì pa (1-3) 
- Ìlànà Ọlọ́run nípa àwọn àjèjì (4-9) 
- Ìlànà tí Ọlọ́run fún àwọn ọmọ Léfì àti àwọn àlùfáà (10-31) 
 
- 45  - 
- Ilẹ̀ mímọ́ tí wọ́n mú wá láti fi ṣe ọrẹ àti ìlú náà (1-6) 
- Ilẹ̀ ìjòyè (7, 8) 
- Kí àwọn ìjòyè jẹ́ olóòótọ́ (9-12) 
- Ọrẹ tí àwọn èèyàn mú wá àti ìjòyè (13-25) 
 
- 46  - 
- Àwọn ọrẹ tí wọ́n á mú wá láwọn ọjọ́ pàtàkì kan (1-15) 
- Ohun ìní tí ìjòyè fi ṣe ogún fúnni (16-18) 
- Àwọn ibi tí wọ́n á ti máa se ọrẹ (19-24) 
 
- 47  
- 48