FÍLÍPÌ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
-  1  - 
- Ìkíni (1, 2) 
- Ọpẹ́ ni fún Ọlọ́run; Àdúrà Pọ́ọ̀lù (3-11) 
- Ìhìn rere ń tẹ̀ síwájú kódà lójú wàhálà (12-20) 
- Ààyè mi jẹ́ ti Kristi, ikú mi jẹ́ èrè (21-26) 
- Ẹ máa hùwà lọ́nà tó yẹ ìhìn rere (27-30) 
 
-  2  - 
- Ìrẹ̀lẹ̀ Kristẹni (1-4) 
- Ìrẹ̀lẹ̀ Kristi àti ìgbéga rẹ̀ (5-11) 
- Ẹ máa ṣiṣẹ́ ìgbàlà yín yọrí (12-18) 
- Ó rán Tímótì àti Ẹpafíródítù (19-30) 
 
-  3  
-  4  - 
- Ìṣọ̀kan, ayọ̀, èrò tí ó tọ́ (1-9) 
- Pọ́ọ̀lù mọyì ẹ̀bùn àwọn ará Fílípì (10-20) 
- Ìkíni tó fi parí ọ̀rọ̀ rẹ̀ (21-23)