Owú
Owú Burúkú
Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:
Jẹ 4:3-8—Kéènì jowú Ébẹ́lì, ó wá bẹ̀rẹ̀ sí í kórìíra rẹ̀, ìyẹn sì mú kó pa á nígbà tó yá
Jẹ 37:9-11—Àwọn ẹ̀gbọ́n Jósẹ́fù jowú ẹ̀
1Sa 18:6-9—Ọba Sọ́ọ̀lù ń jowú Dáfídì, kò sì fọkàn tán an mọ́
Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.
Má bínú, fídíò yìí kò jáde.